AISAYA 11
Ìjọba Tí Ó Tòrò 1 Èèhù kan yóo sọ jáde láti inú kùkùté igi Jese, ẹ̀ka kan yóo sì yọ jáde láti inú àwọn gbòǹgbò rẹ̀. 2 Ẹ̀mí OLUWA yóo…
Ìjọba Tí Ó Tòrò 1 Èèhù kan yóo sọ jáde láti inú kùkùté igi Jese, ẹ̀ka kan yóo sì yọ jáde láti inú àwọn gbòǹgbò rẹ̀. 2 Ẹ̀mí OLUWA yóo…
Orin Ọpẹ́ 1 O óo sọ ní ọjọ́ náà pé, “N óo fi ọpẹ́ fún OLUWA, nítorí pé bí ó tilẹ̀ bínú sí mi, inú rẹ̀ ti rọ̀, ó sì…
Ọlọrun Yóo Jẹ Babiloni Níyà 1 Ìran tí Aisaya ọmọ Amosi rí sí Babiloni: 2 Ẹ ta àsíá ní orí òkè gíga, ẹ gbóhùn sókè sí wọn. Ẹ juwọ́, kí…
Ìpadàbọ̀ láti Ìgbèkùn 1 OLUWA yóo ṣíjú àánú wo Jakọbu yóo tún yan Israẹli, yóo sì fi wọ́n sórí ilẹ̀ wọn. Àwọn àlejò yóo darapọ̀ mọ́ wọn, wọn yóo sì…
OLUWA yóo Pa Moabu Run 1 Ọ̀rọ̀ tí OLUWA sọ nípa ilẹ̀ Moabu nìyí: Nítorí tí a wó ìlú Ari ati Kiri lulẹ̀ ní òru ọjọ́ kan ṣoṣo, ó parí…
Kò sí Ìrètí fún Moabu Mọ́ 1 Wọ́n ti kó àgbò láti Sela, ní ọ̀nà aṣálẹ̀, wọ́n fi ranṣẹ sí aláṣẹ ilẹ̀ náà, ní òkè Sioni. 2 Àwọn ọmọbinrin Moabu…
Ọlọrun Yóo Jẹ Siria ati Israẹli Níyà 1 Ọ̀rọ̀ OLUWA sí ilẹ̀ Damasku nìyí: “Damasku kò ní jẹ́ ìlú mọ́ òkítì àlàpà ni yóo dà. 2 Àwọn ìlú rẹ̀ yóo…
Ọlọrun yóo Jẹ Sudani Níyà 1 Ó ṣe, ní òkè àwọn odò kan ní ilẹ̀ Sudani ibìkan wà tí àwọn ẹyẹ ti ń fò pẹ̀ẹ̀rẹ̀pẹ̀. 2 Ẹni tí ó rán…
Ọlọrun Yóo Jẹ Ijipti Níyà 1 Àsọtẹ́lẹ̀ nípa Ijipti nìyí: OLUWA gun ìkùukùu lẹ́ṣin, ó ń yára bọ̀ wá sí Ijipti. Àwọn oriṣa Ijipti yóo máa gbọ̀n níwájú rẹ̀, ọkàn…
Àmì Wolii tó Wà Níhòhò 1 Ní ọdún tí Sagoni, ọba Asiria, rán olórí ogun rẹ̀ pé kí ó lọ bá ìlú Aṣidodu jagun, tí ó gbógun ti ìlú náà,…