AISAYA 21
Ìran nípa Ìṣubú Babiloni 1 Àsọtẹ́lẹ̀ nípa aṣálẹ̀ etí òkun nìyí: àjálù kan ń já bọ̀ láti inú aṣálẹ̀, láti ilẹ̀ tí ó bani lẹ́rù, ó ń bọ̀ bí ìjì…
Ìran nípa Ìṣubú Babiloni 1 Àsọtẹ́lẹ̀ nípa aṣálẹ̀ etí òkun nìyí: àjálù kan ń já bọ̀ láti inú aṣálẹ̀, láti ilẹ̀ tí ó bani lẹ́rù, ó ń bọ̀ bí ìjì…
Àsọtẹ́lẹ̀ nípa Jerusalẹmu 1 Èyí ni àsọtẹ́lẹ̀ nípa àfonífojì ìran: Kí ni gbogbo yín ń rò tí ẹ fi gun orí òrùlé lọ, 2 ẹ̀yin tí ìlú yín kún fún…
Àsọtẹ́lẹ̀ nípa Tire 1 Àsọtẹ́lẹ̀ nípa Tire nìyí: Ẹ sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn, ẹ̀yin ọlọ́kọ̀ ojú omi ìlú Taṣiṣi; nítorí pé Tire ti di ahoro, láìsí ilé tabi èbúté! Ní ilẹ̀ Kipru…
OLUWA Yóo Jẹ Ilẹ̀ Ayé Níyà 1 Ẹ wò ó! OLUWA yóo fọ́ gbogbo ayé wómúwómú yóo sì sọ ọ́ di ahoro. Yóo dojú rẹ̀ rú, yóo sì fọ́n àwọn…
Orin Ìyìn 1 OLUWA, ìwọ ni Ọlọrun mi. N óo gbé ọ ga: n óo yin orúkọ rẹ. Nítorí pé o ti ṣe àwọn nǹkan ìyanu, o ti ṣe àwọn…
Orin Ìgbàlà 1 Ní àkókò náà, orin tí wọn óo máa kọ ní ilẹ̀ Juda ni pé: “A ní ìlú tí ó lágbára, ó fi ìgbàlà ṣe odi ati ibi…
1 Ní ọjọ́ náà, OLUWA yóo fi idà rẹ̀ tí ó mú, tí ó tóbi, tí ó sì lágbára, pa Lefiatani, ejò tí ó ń fò, Lefiatani, ejò tí ń…
Ìkìlọ̀ fún Ilẹ̀ Israẹli 1 Adé ìgbéraga àwọn ọ̀mùtí Efuraimu gbé! Ẹwà ògo rẹ̀ tí ń ṣá bí ìtànná náà gbé! Ìlú tí ó wà ní òkè àfonífojì dáradára, ohun…
Òkè Sioni Ìlú Dafidi 1 Ó ṣe fún Arieli, Jerusalẹmu, ìlú tí ń jẹ́ pẹpẹ Ọlọrun! Ìlú tí Dafidi pàgọ́ sí. Ẹ ṣe ọdún kan tán, ẹ tún ṣe òmíràn…
Àdéhùn tí kò Wúlò pẹlu Ijipti 1 OLUWA ní: “Àwọn ọmọ aláìgbọràn gbé. Àwọn tí wọn ń dá àbá tí ó yàtọ̀ sí tèmi, tí wọn ń kó ẹgbẹ́ jọ,…