AISAYA 61

Ìròyìn Ayọ̀ Ìdáǹdè 1 Ẹ̀mí OLUWA, Ọlọrun tí bà lé mi, nítorí ó ti fi àmì òróró yàn mí, láti mú ìròyìn ayọ̀ wá fún àwọn tí a ni lára….

AISAYA 62

1 Nítorí Sioni, ń kò ní dákẹ́, nítorí Jerusalẹmu, ń kò ní sinmi, títí ìdáláre rẹ̀ yóo fi yọ bí ìmọ́lẹ̀, tí ìgbàlà rẹ̀ yóo sì tàn bí àtùpà. 2…

AISAYA 63

Ìṣẹ́gun OLUWA lórí Àwọn Orílẹ̀-Èdè 1 “Ta ni ń ti Edomu bọ̀ yìí, tí ó wọ aṣọ àlàárì, tí ń bọ̀ láti Bosira, tí ó yọ bí ọjọ́ ninu aṣọ…

AISAYA 64

1 Ò bá jẹ́ fa awọsanma ya kí o sì sọ̀kalẹ̀, kí àwọn òkè ńlá máa mì tìtì níwájú rẹ; 2 bí ìgbà tí iná ń jó igbó ṣúúrú, tí…

AISAYA 65

Ìyà tí Ọlọrun yóo fi Jẹ Àwọn Ọlọ̀tẹ̀ 1 Mo ṣetán láti mú kí àwọn tí kò bèèrè mi máa wá mi, ati láti fi ara mi han àwọn tí…

AISAYA 66

OLUWA Dá àwọn Orílẹ̀-Èdè Lẹ́jọ́ 1 OLUWA ní: “Ọ̀run ni ìtẹ́ mi, ayé ni àpótí ìtìsẹ̀ mi. Ilé tí ẹ kọ́ fún mi dà? Níbo sì ni ibi ìsinmi mi…