ÀWỌN ADÁJỌ́ 1

Àwọn Ẹ̀yà Juda ati ti Simeoni Ṣẹgun Adonibeseki 1 Lẹ́yìn ikú Joṣua, àwọn ọmọ Israẹli bèèrè lọ́wọ́ OLUWA pé, “Ẹ̀yà wo ni kí ó kọ́kọ́ gbógun ti àwọn ará Kenaani?”…

ÀWỌN ADÁJỌ́ 2

Angẹli OLUWA ní Bokimu 1 Angẹli OLUWA gbéra láti Giligali, ó lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Israẹli ní Bokimu, ó sọ fún wọn pé, “Mo ko yín jáde láti ilẹ̀…

ÀWỌN ADÁJỌ́ 3

Àwọn Orílẹ̀-Èdè Tí Ó Ṣẹ́kù lórí Ilẹ̀ Kenaani 1 OLUWA fi àwọn orílẹ̀-èdè wọnyi sílẹ̀ láti fi dán Israẹli wò, pàápàá jùlọ, gbogbo àwọn ọmọ Israẹli tí wọn kò tíì…

ÀWỌN ADÁJỌ́ 4

Debora ati Baraki 1 Àwọn ọmọ Israẹli tún ṣe ohun tí ó burú lójú OLUWA lẹ́yìn ikú Ehudu. 2 OLUWA bá fi wọ́n lé Jabini ọba Kenaani, tí ó jọba…

ÀWỌN ADÁJỌ́ 5

Orin Debora ati Baraki 1 Debora ati Baraki ọmọ Abinoamu bá kọrin ní ọjọ́ náà pé: 2 Ẹ fi ìyìn fún OLUWA, nítorí pé, àwọn olórí ni wọ́n ṣiwaju ní…

ÀWỌN ADÁJỌ́ 6

Gideoni 1 Àwọn ọmọ Israẹli tún ṣe nǹkan tí ó burú lójú OLUWA, OLUWA sì fi wọ́n lé àwọn ará Midiani lọ́wọ́ fún ọdún meje. 2 Àwọn ará Midiani lágbára…

ÀWỌN ADÁJỌ́ 7

Gideoni Ṣẹgun Àwọn Ará Midiani 1 Nígbà tí ó yá, Gideoni, tí àdàpè rẹ̀ ń jẹ́ Jerubaali, ati àwọn eniyan tí wọ́n wà lọ́dọ̀ rẹ̀ gbéra ní òwúrọ̀ kutukutu ọjọ́…

ÀWỌN ADÁJỌ́ 8

Àwọn Ọmọ Israẹli Ṣẹgun Àwọn Ará Midiani ní Àṣẹ́tán 1 Àwọn ará Efuraimu bèèrè lọ́wọ́ Gideoni pé, “Irú kí ni o ṣe yìí, tí o kò pè wá, nígbà tí…

ÀWỌN ADÁJỌ́ 9

Abimeleki 1 Abimeleki ọmọ Gideoni lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn eniyan ìyá rẹ̀ ní Ṣekemu, ó bá àwọn ati gbogbo ìdílé wọn sọ̀rọ̀, ó ní, 2 kí wọn bèèrè lọ́wọ́ gbogbo…

ÀWỌN ADÁJỌ́ 10

Tola 1 Lẹ́yìn tí Abimeleki kú, Tola ọmọ Pua, ọmọ Dodo, láti inú ẹ̀yà Isakari ni ó dìde tí ó sì gba Israẹli kalẹ̀. Ìlú Ṣamiri tí ó wà ní…