ÀWỌN ADÁJỌ́ 21

Àwọn Ẹ̀yà Bẹnjamini Fẹ́ Iyawo 1 Àwọn ọmọ Israẹli ti búra nígbà tí wọ́n wà ní Misipa pé, “Ẹnikẹ́ni ninu wa kò ní fi ọmọ rẹ̀ fún ará Bẹnjamini.” 2…