ÀWỌN ỌBA KEJI 1

Elija ati Ọba Ahasaya 1 Lẹ́yìn ikú Ahabu ọba, àwọn ará Moabu ṣọ̀tẹ̀ sí Israẹli, wọ́n fẹ́ fi tipátipá gba òmìnira. 2 Ahasaya ọba ṣubú láti orí òkè ilé rẹ̀…

ÀWỌN ỌBA KEJI 2

A Gbé Elija Lọ Sọ́run 1 Nígbà tí àkókò tó fún OLUWA láti fi ààjà gbé Elija lọ sí ọ̀run, Elija ati Eliṣa kúrò ní Giligali. 2 Elija sọ fún…

ÀWỌN ỌBA KEJI 3

Ogun láàrin Israẹli ati Moabu 1 Ní ọdún kejidinlogun tí Jehoṣafati jọba ní Juda, Joramu, ọmọ Ahabu, jọba lórí Israẹli ní Samaria. Ó sì wà lórí oyè fún ọdún mejila….

ÀWỌN ỌBA KEJI 4

Eliṣa Ran Opó Aláìní Kan Lọ́wọ́ 1 Iyawo ọ̀kan ninu àwọn ọmọ àwọn wolii tọ Eliṣa lọ, ó sì sọ fún un pé, “Olúwa mi, iranṣẹ rẹ, ọkọ mi, ti…

ÀWỌN ỌBA KEJI 5

Naamani Gba Ìwòsàn 1 Naamani, olórí ogun Siria, jẹ́ eniyan pataki ati ọlọ́lá níwájú ọba Siria, nítorí pé nípasẹ̀ rẹ̀ ni OLUWA ṣe fún ilẹ̀ Siria ní ìṣẹ́gun. Ó jẹ́…

ÀWỌN ỌBA KEJI 6

Irin Àáké Léfòó 1 Ní ọjọ́ kan àwọn ọmọ àwọn wolii tí wọ́n wà lábẹ́ àkóso Eliṣa sọ fún un pé, “Ibi tí à ń gbé kéré jù fún wa….

ÀWỌN ỌBA KEJI 7

1 Eliṣa dáhùn pé, “Gbọ́ ọ̀rọ̀ OLUWA, ní àkókò yìí lọ́la, ní ẹnubodè Samaria, àwọn eniyan yóo ra òṣùnwọ̀n ìyẹ̀fun kíkúnná kan, tabi òṣùnwọ̀n ọkà baali meji ní ìwọ̀n ṣekeli…

ÀWỌN ỌBA KEJI 8

Obinrin Ará Ṣunemu náà Pada 1 Eliṣa sọ fún obinrin ará Ṣunemu, ẹni tí Eliṣa jí ọmọ rẹ̀ tí ó kú pé, “OLUWA yóo rán ìyàn sí ilẹ̀ yìí fún…

ÀWỌN ỌBA KEJI 9

A fi Òróró Yan Jehu ní Ọba Israẹli 1 Eliṣa pe ọ̀kan ninu àwọn ọmọ àwọn wolii, ó sọ fún un pé, “Ṣe kánkán, kí o lọ sí Ramoti Gileadi…

ÀWỌN ỌBA KEJI 10

A Pa Àwọn Ọmọ Ọba Ahabu 1 Ahabu ní aadọrin ọmọkunrin tí wọn ń gbé Samaria. Jehu kọ ìwé ranṣẹ sí àwọn olórí ìlú ati àwọn àgbààgbà ati àwọn olùtọ́jú…