ÀWỌN ỌBA KEJI 11

Atalaya Ayaba Juda 1 Ní kété tí Atalaya, ìyá ọba Ahasaya gbọ́ nípa ikú ọmọ rẹ̀, ó pa gbogbo ìdílé ọba run. 2 Joaṣi ọmọ Ahasaya nìkan ni kò pa…

ÀWỌN ỌBA KEJI 12

Joaṣi Ọba Juda 1 Ní ọdún keje tí Jehu jọba ní Israẹli ni Joaṣi jọba ní ilẹ̀ Juda, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ogoji ọdún. Sibaya tí…

ÀWỌN ỌBA KEJI 13

Jehoahasi Ọba Israẹli 1 Ní ọdún kẹtalelogun tí Joaṣi, ọmọ Ahasaya, jọba ní Juda ni Jehoahasi, ọmọ Jehu, jọba lórí Israẹli ní Samaria, ó jọba fún ọdún mẹtadinlogun. 2 Ó…

ÀWỌN ỌBA KEJI 14

Amasaya Ọba Juda 1 Ní ọdún keji tí Jehoaṣi ọmọ Jehoahasi jọba ní Israẹli ni Amasaya ọmọ Joaṣi jọba ní Juda. 2 Ẹni ọdún mẹẹdọgbọn ni nígbà tí ó jọba,…

ÀWỌN ỌBA KEJI 15

Asaraya Ọba Juda 1 Ní ọdún kẹtadinlọgbọn tí Jeroboamu jọba ní Israẹli ni Asaraya ọmọ Amasaya, jọba ní Juda. 2 Ẹni ọdún mẹrindinlogun ni nígbà tí ó jọba, ó sì…

ÀWỌN ỌBA KEJI 16

Ahasi, Ọba Juda 1 Ní ọdún kẹtadinlogun tí Peka, ọmọ Remalaya, jọba ní Israẹli, ni Ahasi, ọmọ Jotamu, jọba ní Juda. 2 Ẹni ogún ọdún ni Ahasi nígbà tí ó…

ÀWỌN ỌBA KEJI 17

Hoṣea Ọba Israẹli 1 Ní ọdún kejila tí Ahasi jọba ní Juda, ni Hoṣea ọmọ Ela jọba lórí Israẹli, ní Samaria, ó sì jọba fún ọdún mẹsan-an. 2 Ó ṣe…

ÀWỌN ỌBA KEJI 18

Hesekaya, Ọba Juda 1 Ní ọdún kẹta tí Hoṣea, ọmọ Ela, jọba ní Israẹli ni Hesekaya, ọmọ Ahasi jọba ní Juda. 2 Ẹni ọdún mẹẹdọgbọn ni nígbà tí ó jọba,…

ÀWỌN ỌBA KEJI 19

Ọba Bèèrè Ìmọ̀ràn Lọ́wọ́ Aisaya 1 Nígbà tí Hesekaya ọba gbọ́, ó fa aṣọ rẹ̀ ya, ó fi aṣọ ọ̀fọ̀ bora, ó bá lọ sinu ilé OLUWA. 2 Ó rán…

ÀWỌN ỌBA KEJI 20

Àìsàn Hesekaya Ọba, ati Ìwòsàn Rẹ̀ 1 Ní àkókò kan Hesekaya ṣàìsàn tóbẹ́ẹ̀ tí ó fẹ́rẹ̀ kú. Wolii Aisaya ọmọ Amosi, wá sọ́dọ̀ rẹ̀, ó sọ fún un pé, “OLUWA…