ÀWỌN ỌBA KINNI 1

Ìgbà Ogbó Dafidi 1 Ní àkókò yìí, Dafidi ọba ti di arúgbó. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé aṣọ tí ó nípọn ni wọ́n fi ń bò ó, òtútù a tún…

ÀWỌN ỌBA KINNI 2

Ìkìlọ̀ Ìkẹyìn Tí Dafidi ṣe fún Solomoni 1 Nígbà tí ó kù dẹ̀dẹ̀ kí Dafidi jáde láyé, ó pe Solomoni, ọmọ rẹ̀, ó sì kìlọ̀ fún un pé, 2 “Ó…

ÀWỌN ỌBA KINNI 3

Solomoni Bẹ̀bẹ̀ fún Ọgbọ́n 1 Solomoni gbé ọmọ Farao, ọba Ijipti níyàwó, ó fi bá ọba Farao dá majẹmu àjọṣepọ̀ láàrin wọn. Solomoni mú iyawo náà wá sí ìlú Dafidi…

ÀWỌN ỌBA KINNI 4

Àwọn Òṣìṣẹ́ Solomoni 1 Solomoni jọba gbogbo ilẹ̀ Israẹli, 2 Orúkọ àwọn olórí ninu àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ nìwọ̀nyí: Asaraya, ọmọ Sadoku ni alufaa. 3 Elihorefi ati Ahija, meji ninu àwọn…

ÀWỌN ỌBA KINNI 5

Solomoni Palẹ̀mọ́ láti Kọ́ Tẹmpili 1 Nígbà tí Hiramu, ọba Tire, gbọ́ pé Solomoni ni ó gun orí oyè lẹ́yìn baba rẹ̀, ó rán oníṣẹ́ sí i; nítorí ọ̀rẹ́ ni…

ÀWỌN ỌBA KINNI 6

Solomoni Kọ́ Tẹmpili 1 Nígbà tí ó di ọrinlenirinwo (480) ọdún tí àwọn ọmọ Israẹli kúrò ní ilẹ̀ Ijipti, ní ọdún kẹrin tí Solomoni gun orí oyè ní Israẹli, ní…

ÀWỌN ỌBA KINNI 7

Ààfin Solomoni 1 Ọdún mẹtala ni Solomoni fi parí kíkọ́ ilé ti ara rẹ̀. 2 Ọ̀kan ninu àwọn ilé tí ó kọ́ sí ààfin náà ni Ilé Igbó Lẹbanoni. Ilé…

ÀWỌN ỌBA KINNI 8

Wọ́n Gbé Àpótí Ẹ̀rí Wá sí inú Tẹmpili 1 Lẹ́yìn náà, Solomoni ọba ranṣẹ sí àwọn àgbààgbà Israẹli: àwọn olórí ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan, ati gbogbo àwọn olórí ìdílé kọ̀ọ̀kan, ó pè…

ÀWỌN ỌBA KINNI 9

Ọlọrun Tún Fara han Solomoni 1 Lẹ́yìn tí Solomoni ọba ti kọ́ ilé OLUWA ati ààfin rẹ̀ tán, ati gbogbo ilé tí ó fẹ́ kọ́. 2 OLUWA tún fi ara…

ÀWỌN ỌBA KINNI 10

Ìbẹ̀wò Ọbabinrin Ìlú Ṣeba 1 Nígbà tí ọbabinrin Ṣeba gbọ́ òkìkí ọgbọ́n Solomoni, ó wá sí Jerusalẹmu láti fi àwọn ìbéèrè tí ó takókó dán an wò. 2 Ó kó…