ÀWỌN ỌBA KINNI 21
Ọgbà Àjàrà Naboti 1 Ọkunrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Naboti, ará Jesireeli, ní ọgbà àjàrà kan. Ní Jesireeli ni ọgbà yìí wà, lẹ́bàá ààfin Ahabu, ọba Samaria. 2…

Wolii Mikaaya Kìlọ̀ fún Ahabu 1 Fún ọdún mẹta lẹ́yìn èyí, kò sí ogun rárá láàrin ilẹ̀ Israẹli ati ilẹ̀ Siria. 2 Nígbà tí ó di ọdún kẹta, Jehoṣafati, ọba…