EFESU 1

Ìkíni 1 Èmi Paulu, aposteli Kristi Jesu nípa ìfẹ́ Ọlọrun, ni mò ń kọ ìwé yìí sí àwọn eniyan Ọlọrun tí ó wà ní Efesu, àwọn tí wọ́n jẹ́ olóòótọ́…

EFESU 2

Láti Inú Ikú sí Inú Ìyè 1 Nígbà kan rí ẹ jẹ́ òkú ninu ìwàkiwà ati ẹ̀ṣẹ̀ yín. 2 Nígbà náà ẹ̀ ń hùwà gẹ́gẹ́ bí ẹni ti ayé yìí,…

EFESU 3

Iṣẹ́ Paulu láàrin Àwọn Tí Kì í Ṣe Juu 1 Ìdí rẹ̀ nìyí tí èmi Paulu fi di ẹlẹ́wọ̀n fún Kristi Jesu nítorí ti ẹ̀yin tí ẹ kì í ṣe…

EFESU 4

Ìṣọ̀kan Ara Kristi 1 Nítorí náà, èmi tí mo di ẹlẹ́wọ̀n nítorí ti Oluwa, ń bẹ̀ yín pé kí ẹ máa hùwà gẹ́gẹ́ bí ó ti yẹ, bí irú ìpè…

EFESU 5

Gbígbé ninu Ìmọ́lẹ̀ 1 Nítorí náà, gẹ́gẹ́ bí àyànfẹ́ ọmọ, ẹ fi ìwà jọ Ọlọrun. 2 Ẹ máa rìn ninu ìfẹ́ gẹ́gẹ́ bí Kristi ti fẹ́ wa, tí ó fi…

EFESU 6

Ọmọ ati Òbí 1 Ẹ̀yin ọmọ, ẹ máa gbọ́ ti àwọn òbí yín nítorí pé bẹ́ẹ̀ ni ó dára. 2 “Bọ̀wọ̀ fún baba ati ìyá rẹ.” Èyí níí ṣe òfin…