ẸKISODU 11

Mose Kéde Ikú Àwọn Àkọ́bí 1 Nígbà tí ó yá, OLUWA sọ fún Mose pé, “Ó ku ìyọnu kan péré, tí n óo mú bá Farao ati ilẹ̀ Ijipti, lẹ́yìn…

ẸKISODU 12

Àjọ Ìrékọjá 1 OLUWA sọ fún Mose ati Aaroni ní ilẹ̀ Ijipti pé, 2 “Oṣù yìí ni yóo jẹ́ oṣù kinni ọdún fún yín. 3 Ẹ sọ fún gbogbo ìjọ…

ẸKISODU 13

Yíya Àwọn Àkọ́bí sí Mímọ́ 1 OLUWA sọ fún Mose pé, 2 “Ya gbogbo àwọn àkọ́bí sí mímọ́ fún mi, ohunkohun tí ó bá ti jẹ́ àkọ́bí láàrin àwọn eniyan…

ẸKISODU 14

Líla Òkun Pupa Kọjá 1 OLUWA bá rán Mose, ó ní, 2 “Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé kí wọ́n yipada, kí wọ́n sì pàgọ́ siwaju Pi Hahirotu, láàrin Migidoli…

ẸKISODU 15

Orin Mose 1 Lẹ́yìn náà, Mose ati àwọn ọmọ Israẹli kọ orin yìí sí OLUWA, wọ́n ní: “N óo kọrin sí OLUWA, nítorí pé, ó ti ja àjàṣẹ́gun tí ó…

ẸKISODU 16

Mana ati Àparò 1 Nígbà tí ó yá, gbogbo ìjọ eniyan Israẹli jáde kúrò ní Elimu, wọ́n lọ sí aṣálẹ̀ Sini tí ó wà ní ààrin Elimu ati Sinai, ní…

ẸKISODU 17

Omi Jáde láti Inú Àpáta 1 Gbogbo ìjọ eniyan Israẹli gbéra láti aṣálẹ̀ Sini, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí lọ láti ibùsọ̀ kan dé ekeji, gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí OLUWA pa fún…

ẸKISODU 18

Jẹtiro Lọ Bẹ Mose Wò 1 Jẹtiro, alufaa àwọn ará Midiani, baba iyawo Mose, gbọ́ gbogbo ohun tí Ọlọrun ti ṣe fún Mose ati fún Israẹli, àwọn eniyan rẹ̀, ati…

ẸKISODU 19

Àwọn Ọmọ Israẹli ní Òkè Sinai 1 Ní oṣù kẹta tí àwọn eniyan Israẹli kúrò ní ilẹ̀ Ijipti ni wọ́n dé aṣálẹ̀ Sinai. 2 Refidimu ni wọ́n ti gbéra wá…

ẸKISODU 20

Òfin Mẹ́wàá 1 Ọlọrun sì sọ ọ̀rọ̀ wọnyii, ó ní, 2 “Èmi ni OLUWA Ọlọrun yín, tí ó mu yín jáde láti ilẹ̀ Ijipti, ní oko ẹrú tí ẹ wà:…