ẸKISODU 31

Àwọn Òṣìṣẹ́ fún Àgọ́ OLUWA 1 OLUWA sọ fún Mose pé, 2 “Wò ó, mo ti pe Besaleli ọmọ Uri, ọmọ ọmọ Huri, láti inú ẹ̀yà Juda. 3 Mo sì…

ẸKISODU 32

Ère Mààlúù Wúrà 1 Nígbà tí àwọn eniyan náà rí i pé Mose ń pẹ́ jù lórí òkè, wọ́n kó ara wọn jọ, wọ́n tọ Aaroni lọ; wọ́n sọ fún…

ẸKISODU 33

OLUWA Pàṣẹ Pé Kí Àwọn Eniyan Israẹli Kúrò ní Òkè Sinai 1 OLUWA tún pe Mose, ó ní, “Dìde kúrò níhìn-ín, ìwọ ati àwọn eniyan tí o kó wá láti…

ẸKISODU 34

Àwọn Wàláà Òkúta Keji 1 Ọlọrun sọ fún Mose pé, “Gbẹ́ wàláà òkúta meji bíi ti àkọ́kọ́, n óo sì kọ àwọn ọ̀rọ̀ tí mo kọ sára wàláà ti àkọ́kọ́…

ẸKISODU 35

Àwọn ìlànà fún Ọjọ́ Ìsinmi 1 Mose pe gbogbo àwọn ọmọ Israẹli jọ, ó wí fún wọn pé, “Àwọn nǹkan tí OLUWA pa láṣẹ pé kí ẹ máa ṣe nìwọ̀nyí:…

ẸKISODU 36

1 “Kí Besaleli, ati Oholiabu ati olukuluku àwọn tí OLUWA fún ní ìmọ̀ ati òye, láti ṣe èyíkéyìí ninu iṣẹ́ tí ó jẹmọ́ kíkọ́ ilé mímọ́ náà, ṣe é bí…

ẸKISODU 37

Kíkan Àpótí Ẹ̀rí 1 Besaleli fi igi akasia àpótí ẹ̀rí náà, gígùn rẹ̀ jẹ́ igbọnwọ meji ààbọ̀, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ igbọnwọ kan ààbọ̀, ó sì ga ní igbọnwọ kan ààbọ̀….

ẸKISODU 38

Ṣíṣe Pẹpẹ fún Ẹbọ Sísun 1 Ó fi igi akasia ṣe pẹpẹ ẹbọ sísun, bákan náà ni gígùn ati fífẹ̀ pẹpẹ náà rí, wọ́n jẹ́ igbọnwọ marun-un marun-un, gíga rẹ̀…

ẸKISODU 39

Dídá Ẹ̀wù Àwọn Alufaa 1 Wọ́n fi aṣọ aláwọ̀ aró, ati ti elése àlùkò, ati aṣọ pupa, rán ẹ̀wù aláràbarà tí àwọn alufaa yóo máa wọ̀ ninu ibi mímọ́ náà…

ẸKISODU 40

Kíkọ́ ati Yíya Àgọ́ Ìpàdé OLUWA sí Mímọ́ 1 OLUWA sọ fún Mose pé, 2 “Kọ́ àgọ́ ìpàdé ní ọjọ́ kinni oṣù kinni. 3 Kí o sì gbé àpótí ẹ̀rí…