ẸKÚN JEREMAYA 1

Ìbànújẹ́ Jerusalẹmu 1 Ẹ wò ó bí ìlú tí ó kún fún eniyan tẹ́lẹ̀ ti di ahoro, tí ó wá dàbí opó! Ìlú tí ó tóbi láàrin àwọn orílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀!…

ẸKÚN JEREMAYA 2

Ìyà Tí OLUWA Fi Jẹ Jerusalẹmu 1 Ẹ wò bí OLUWA ti fi ibinu fi ìkùukùu bo Sioni mọ́lẹ̀. Ó ti wọ́ ògo Israẹli lu láti òkè ọ̀run sórí ilẹ̀…

ẸKÚN JEREMAYA 3

Ìjìyà, Ìrònúpìwàdà ati Ìrètí 1 Èmi ni mo mọ bí eniyan tií rí ìpọ́njú, tí mo mọ bí Ọlọrun tií fi ibinu na eniyan ní pàṣán. 2 Ó lé mi…

ẸKÚN JEREMAYA 4

Jerusalẹmu, Lẹ́yìn Ìṣubú Rẹ̀ 1 Wo bí wúrà ti dọ̀tí, tí ojúlówó wúrà sì yipada; tí àwọn òkúta Tẹmpili mímọ́ sì fọ́nká ní gbogbo ìkóríta. 2 Ẹ wo àwọn ọdọmọkunrin…

ẸKÚN JEREMAYA 5

Adura fún Àánú 1 OLUWA, ranti ohun tí ó ṣẹlẹ̀ sí wa, Ṣe akiyesi ẹ̀sín wa. 2 Àwọn ilẹ̀ àjogúnbá ẹni ẹlẹ́ni, ilé wa sì ti di ti àwọn àjèjì….