ẸSIRA 1

Kirusi Ọba Pàṣẹ pé kí Àwọn Juu Pada 1 Ní ọdún kinni ìjọba Kirusi, ọba Pasia, kí àsọtẹ́lẹ̀ láti ẹnu wolii Jeremaya lè ṣẹ, OLUWA fi sí Kirusi ọba lọ́kàn…

ẸSIRA 2

Àwọn tí Wọ́n Pada ti Oko Ẹrú Dé 1 Àwọn ọmọ Juda wọnyi ni wọ́n pada dé láti oko ẹrú ní Babiloni, níbi tí Nebukadinesari, ọba Babiloni, kó wọn lẹ́rú…

ẸSIRA 3

Wọ́n tún Bẹ̀rẹ̀ Ìjọ́sìn 1 Ní oṣù keje tí àwọn ọmọ Israẹli ti pada sí ìlú wọn, gbogbo wọn péjọ sí Jerusalẹmu. 2 Jeṣua, ọmọ Josadaki pẹlu àwọn alufaa ẹgbẹ́…

ẸSIRA 4

Àtakò Sí Títún Ilé Ọlọrun Kọ́ 1 Nígbà ti àwọn ọ̀tá Juda ati ti Bẹnjamini gbọ́ pé àwọn tí wọ́n ti ìgbèkùn dé ti bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ ilé OLUWA Ọlọrun…

ẸSIRA 5

Iṣẹ́ Kíkọ́ Tẹmpili Tún Bẹ̀rẹ̀ 1 Wolii Hagai ati wolii Sakaraya, ọmọ Ido, bẹ̀rẹ̀ sí sọ àsọtẹ́lẹ̀ fún àwọn Juu tí wọ́n wà ni Juda ati Jerusalẹmu ní orúkọ Ọlọrun…

ẸSIRA 6

Wọ́n Rí Àkọsílẹ̀ Àṣẹ tí Kirusi Ọba Pa 1 Dariusi ọba pàṣẹ pé kí wọ́n wádìí fínnífínní ninu àwọn ìwé àkọsílẹ̀ tí ó wà ní ààfin, ní ilẹ̀ Babiloni. 2…

ẸSIRA 7

Ẹsira Dé sí Jerusalẹmu 1 Lẹ́yìn náà, ní àkókò ìjọba Atasasesi, ọba Pasia, ọkunrin kan wà, orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ẹsira, ọmọ Seraaya, ọmọ Asaraya, ọmọ Hilikaya, 2 ọmọ Ṣalumu,…

ẸSIRA 8

Àwọn tí Wọ́n Pada láti Oko Ẹrú 1 Àkọsílẹ̀ àwọn eniyan ati àwọn baálé baálé tí wọ́n bá mi pada wá láti Babiloni ní àkókò Atasasesi, ọba, nìyí: 2 Ninu…

ẸSIRA 9

Ẹsira gbọ́ pé Àwọn Ọmọ Israẹli ń fẹ́ Àwọn Ọmọbinrin tí wọn kì í ṣe Juu 1 Lẹ́yìn nǹkan wọnyi, àwọn olórí àwọn ọmọ Israẹli wá sọ́dọ̀ mi, wọ́n ní:…

ẸSIRA 10

Ètò láti fi Òpin sí Igbeyawo láàrin àwọn Juu ati àwọn tí Wọn kì í ṣe Juu 1 Bí Ẹsira ti ń gbadura, tí ó ń jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀, tí ó…