ẸSITA 1

Ayaba Faṣiti Rí Ahasu-erusi Ọba Fín 1 Ní àkókò tí Ahasu-erusi jọba ní ilẹ̀ Pasia, ìjọba rẹ̀ tàn dé agbègbè mẹtadinlaadoje (127), láti India títí dé Kuṣi ní ilẹ̀ Etiopia….

ẸSITA 2

Ẹsita Di Ayaba 1 Nígbà tí ó yá, tí ibinu ọba rọlẹ̀, ó ranti ohun tí Faṣiti ṣe, ati àwọn àṣẹ tí òun pa nípa rẹ̀. 2 Àwọn iranṣẹ ọba…

ẸSITA 3

Hamani Dìtẹ̀ láti Pa Àwọn Juu Run 1 Ahasu-erusi ọba gbé Hamani, ọmọ Hamedata, ará Agagi, ga ju gbogbo àwọn ìjòyè yòókù lọ. 2 Gbogbo àwọn olóyè ní ẹnu ọ̀nà…

ẸSITA 4

Modekai Wá Ìrànlọ́wọ́ Ẹsita 1 Nígbà tí Modekai gbọ́ gbogbo ohun tí ó ṣẹlẹ̀, ó fa aṣọ rẹ̀ ya. Ó fi àkísà ati eérú bo ara rẹ̀. Ó kígbe lọ…

ẸSITA 5

Ẹsita Pe Ọba ati Hamani sí Àsè 1 Ní ọjọ́ kẹta, Ẹsita wọ aṣọ oyè rẹ̀, ó dúró ní àgbàlá ààfin ọba, ó kọjú sí gbọ̀ngàn ọba. Ọba jókòó lórí…

ẸSITA 6

Ọba Dá Modekai Lọ́lá 1 Ní òru ọjọ́ náà, ọba kò lè sùn. Ó bá pàṣẹ pé kí wọ́n gbé ìwé àkọsílẹ̀ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìjọba rẹ̀ wá, kí wọ́n sì…

ẸSITA 7

1 Ọba ati Hamani lọ bá Ayaba Ẹsita jẹ àsè. 2 Ní ọjọ́ keji, bí wọ́n ti ń mu ọtí, ọba tún bi Ẹsita pé, “Ẹsita, Ayaba, kí ni ẹ̀bẹ̀…

ẸSITA 8

Wọ́n fún Àwọn Juu Láṣẹ láti Bá Àwọn Ọ̀tá Wọn Jà 1 Ní ọjọ́ náà gan-an ni ọba Ahasu-erusi fún Ẹsita Ayaba ní ilé Hamani, ọ̀tá àwọn Juu. Ẹsita wá…

ẸSITA 9

Àwọn Juu Pa Àwọn Ọ̀tá Wọn Run 1 Ní ọjọ́ kẹtala oṣù Adari tíí ṣe oṣù kejila, nígbà tí wọ́n ń múra láti ṣe ohun tí òfin ọba wí, ní…

ẸSITA 10

Títóbi Ahasu-erusi ati Modekai 1 Ọba Ahasu-erusi pàṣẹ pé kí àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n jìnnà ati àwọn tí wọn ń gbé etíkun máa san owó orí. 2 Gbogbo iṣẹ́ agbára…