HEBERU 11
Igbagbọ 1 Igbagbọ ni ìdánilójú ohun tí à ń retí, ẹ̀rí tí ó dájú nípa àwọn ohun tí a kò rí. 2 Igbagbọ ni àwọn àgbà àtijọ́ ní, tí wọ́n…
Igbagbọ 1 Igbagbọ ni ìdánilójú ohun tí à ń retí, ẹ̀rí tí ó dájú nípa àwọn ohun tí a kò rí. 2 Igbagbọ ni àwọn àgbà àtijọ́ ní, tí wọ́n…
Ìtọ́ni ti Oluwa 1 Níwọ̀n ìgbà tí a ní àwọn tí wọn ń jẹ́rìí sí agbára igbagbọ, tí wọ́n yí wa ká bí awọsanma báyìí, ẹ jẹ́ kí á pa…
Ìsìn Tí Ó Wu Ọlọrun 1 Àwọn onigbagbọ níláti fẹ́ràn ara wọn. 2 Ẹ má gbàgbé láti máa ṣe àlejò nítorí nípa àlejò ṣíṣe àwọn ẹlòmíràn ti ṣe àwọn angẹli…