HOSIA 11
Ìfẹ́ Ọlọrun sí Àwọn Eniyan Rẹ̀, Ọlọ̀tẹ̀ 1 OLUWA ní, “Nígbà tí Israẹli wà ní ọmọde, mo fẹ́ràn rẹ̀, láti ilẹ̀ Ijipti ni mo sì ti pe ọmọ mi jáde….
Ìfẹ́ Ọlọrun sí Àwọn Eniyan Rẹ̀, Ọlọ̀tẹ̀ 1 OLUWA ní, “Nígbà tí Israẹli wà ní ọmọde, mo fẹ́ràn rẹ̀, láti ilẹ̀ Ijipti ni mo sì ti pe ọmọ mi jáde….
1 “Asán ati ìbàjẹ́ ni gbogbo nǹkan tí Efuraimu ń ṣe látàárọ̀ dalẹ́. Wọ́n ń parọ́ kún irọ́, bẹ́ẹ̀ ni ìwà ipá wọn ń pọ̀ sí i. Wọ́n ń bá…
Paríparí Ìdájọ́ Israẹli 1 Tẹ́lẹ̀ rí, bí ẹ̀yà Efuraimu bá sọ̀rọ̀, àwọn eniyan a máa wárìrì; wọ́n níyì láàrin àwọn ẹ̀yà Israẹli yòókù, ṣugbọn nítorí pé wọ́n bọ oriṣa Baali,…
Ẹ̀bẹ̀ Hosia fún Israẹli 1 Ẹ pada tọ OLUWA Ọlọrun yín lọ, ẹ̀yin ọmọ Israẹli, nítorí pé ẹ ti kọsẹ̀ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ yín. 2 Ẹ pada sọ́dọ̀ OLUWA, kí ẹ…