ÌṢE ÀWỌN APOSTELI 21
Ìrìn Àjò Paulu sí Jerusalẹmu 1 Nígbà tí a dágbére fún wọn tán, ọkọ̀ ṣí. A wá lọ tààrà sí Kosi. Ní ọjọ́ keji a dé Rodọsi. Láti ibẹ̀ a…
Ìrìn Àjò Paulu sí Jerusalẹmu 1 Nígbà tí a dágbére fún wọn tán, ọkọ̀ ṣí. A wá lọ tààrà sí Kosi. Ní ọjọ́ keji a dé Rodọsi. Láti ibẹ̀ a…
1 Ó ní “Ẹ̀yin ará mi ati ẹ̀yin baba wa, ẹ fetí sí ẹjọ́ tí mo ní í rò fun yín nisinsinyii.” 2 Nígbà tí wọ́n gbọ́ tí ó ń…
1 Paulu kọjú sí àwọn ìgbìmọ̀, ó ní, “Ẹ̀yin ará, ní gbogbo ìgbé-ayé mi, ọkàn mí mọ́ níwájú Ọlọrun títí di òní.” 2 Bí ó ti sọ báyìí, bẹ́ẹ̀ ni…
Ẹ̀sùn Tí Wọ́n fi Kan Paulu 1 Lẹ́yìn ọjọ́ marun-un, Anania olórí Alufaa dé pẹlu àwọn àgbààgbà ati agbẹjọ́rò kan tí ń jẹ́ Tatulu. Wọ́n ro ẹjọ́ Paulu fún gomina….
Paulu Gbé Ẹjọ́ Rẹ̀ Lọ siwaju Ọba Kesari 1 Lẹ́yìn ọjọ́ mẹta tí Fẹstu dé sí agbègbè ibi iṣẹ́ rẹ̀, ó lọ sí Jerusalẹmu láti Kesaria. 2 Àwọn olórí alufaa…
Paulu Sọ Ti Ẹnu Rẹ̀ níwájú Agiripa 1 Agiripa wá yíjú sí Paulu, ó ní, “Ọ̀rọ̀ kàn ọ́. Sọ tìrẹ.” Paulu bá nawọ́, ó bẹ̀rẹ̀ sí ro ẹjọ́ tirẹ̀. Ó…
Paulu Wọkọ̀ Lọ sí Romu 1 Nígbà tí wọ́n pinnu láti fi wá ranṣẹ sí Itali, wọ́n fi Paulu ati àwọn ẹlẹ́wọ̀n mìíràn lé balogun ọ̀rún kan tí ó ń…
Ohun tí Paulu Ṣe ní Erékùṣù Mẹlita 1 Nígbà tí a ti gúnlẹ̀ ní alaafia tán ni a tó mọ̀ pé Mẹlita ni wọ́n ń pe erékùṣù náà. 2 Àwọn…