ISIKIẸLI 1

Ìtẹ́ Ọlọrun 1 Ní ọjọ́ karun-un oṣù kẹrin, ní ọgbọ̀n ọdún, èmi, Isikiẹli, ọmọ Busi, wà láàrin àwọn tí wọ́n kó ní ìgbèkùn lọ sí ilẹ̀ Babiloni. A wà lẹ́bàá…

ISIKIẸLI 2

1 Ó sọ fún mi pé, “Ọmọ eniyan, dìde dúró, mo fẹ́ bá ọ sọ̀rọ̀.” 2 Bí ó ti ń bá mi sọ̀rọ̀, ẹ̀mí OLUWA wọ inú mi, ó gbé…

ISIKIẸLI 3

1 Ó sọ fún mi pé, “Ọmọ Eniyan, jẹ ohun tí a fún ọ; jẹ ìwé tí a ká yìí, kí o sì lọ bá ilé Israẹli sọ̀rọ̀.” 2 Mo…

ISIKIẸLI 4

Isikiẹli Gbé Òfin Jáde lórí Ìwà Ìbàjẹ́ ní Jerusalẹmu 1 OLUWA ní: “Ìwọ ọmọ eniyan, mú bulọọku kan kí o gbé e ka iwájú rẹ, kí o sì ya àwòrán…

ISIKIẸLI 5

Isikiẹli Gé Irun Rẹ̀ 1 OLUWA ní: “Ìwọ ọmọ eniyan, mú idà kan tí ó bá mú, lò ó gẹ́gẹ́ bí abẹ ìfárí, kí o fi fá orí ati irùngbọ̀n…

ISIKIẸLI 6

Ọlọrun fi Ìbọ̀rìṣà Gégùn-ún 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: 2 “Ọmọ eniyan, dojú kọ àwọn òkè Israẹli kí o sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ sí wọn. 3 Sọ pé, ‘Ẹ̀yin…

ISIKIẸLI 7

Òpin ti dé Tán fún Israẹli 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, ohun tí èmi OLUWA Ọlọrun sọ nípa ilẹ̀ Israẹli ni pé: òpin ti…

ISIKIẸLI 8

Ìwà Ìbọ̀rìṣà Ní Jerusalẹmu 1 Ní ọjọ́ karun-un, oṣù kẹfa ọdún kẹfa tí a ti wà ní ìgbèkùn, bí mo ti jókòó ninu ilé mi, tí àwọn àgbààgbà Juda sì…

ISIKIẸLI 9

Wọ́n Jẹ Jerusalẹmu Níyà 1 Lẹ́yìn náà, Ọlọrun kígbe sí mi létí, ó ní, “Ẹ súnmọ́bí, ẹ̀yin tí ẹ óo pa ìlú yìí run, kí olukuluku mú nǹkan ìjà rẹ̀…

ISIKIẸLI 10

Ògo OLUWA Kúrò Ninu Tẹmpili Náà 1 Lẹ́yìn náà, mo wo orí àwọn Kerubu, mo rí kinní kan róbótó róbótó, wọ́n dàbí òkúta safire, ìrísí wọn dàbí ìtẹ́. 2 Ọlọrun…