ISIKIẸLI 11
(OLUWA Bá Jerusalẹmu Wí) 1 Ẹ̀mí gbé mi lọ sí ẹnu ọ̀nà ilé OLUWA tí ó kọjú sí ìhà ìlà oòrùn. Àwọn ọkunrin mẹẹdọgbọn kan wà lẹ́nu ọ̀nà náà, mo…
(OLUWA Bá Jerusalẹmu Wí) 1 Ẹ̀mí gbé mi lọ sí ẹnu ọ̀nà ilé OLUWA tí ó kọjú sí ìhà ìlà oòrùn. Àwọn ọkunrin mẹẹdọgbọn kan wà lẹ́nu ọ̀nà náà, mo…
Wolii Gẹ́gẹ́ Bí Ẹni Tí Ó sá fógun 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, ààrin àwọn olóríkunkun ni o wà: àwọn tí wọ́n ní ojú,…
Ìran Ibi Nípa Àwọn Ọkunrin Wolii Èké 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní, 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, sọ àsọtẹ́lẹ̀ fún àwọn wolii Israẹli. Sọ àsọtẹ́lẹ̀, kí o sì wí…
Ọlọrun Fi Ìbọ̀rìṣà Gégùn-ún 1 Àwọn àgbààgbà Israẹli kan tọ̀ mí wá, wọ́n jókòó siwaju mi. 2 OLUWA bá bá mi sọ̀rọ̀, 3 ó ní: “Ìwọ ọmọ eniyan, àwọn ọkunrin…
Òwe Nípa Igi Àjàrà 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, ọ̀nà wo ni ẹ̀ka igi àjàrà gbà dára ju ẹ̀ka igi yòókù lọ; àní igi…
Ìtàn Jerusalẹmu 1 OLUWA tún bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, fi nǹkan ìríra tí Jerusalẹmu ń ṣe hàn án, 3 kí o sì sọ fún un…
Òwe Nípa Àwọn Ẹyẹ Idì ati Àjàrà 1 OLUWA tún bá mi sọ̀rọ̀, ó ní, 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, pa àlọ́ kan kí o sì fi òwe bá àwọn ọmọ…
Iṣẹ́ Ẹnìkọ̀ọ̀kan 1 OLUWA tún bá mi sọ̀rọ̀, ó bi mí pé: 2 “Kí ni ẹ rí tí ẹ fi ń pa irú òwe yìí nípa ilẹ̀ Israẹli, tí ẹ̀…
Orin Arò 1 OLUWA ní kí n sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn nítorí àwọn olórí Israẹli, 2 kí n sọ pé: Abo kinniun pataki ni ìyá rẹ láàrin àwọn kinniun! Ó dùbúlẹ̀ láàrin…
Ìfẹ́ OLUWA ati Àìbìkítà Eniyan 1 Ní ọjọ́ kẹwaa oṣù karun-un, ọdún keje tí a ti wà ní ìgbèkùn, àwọn àgbààgbà Israẹli kan wá láti wádìí ọ̀rọ̀ lọ́dọ̀ OLUWA, wọ́n…