ISIKIẸLI 21
Idà OLUWA 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀; ó ní, 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, kọjú sí Jerusalẹmu kí o sọ àsọtẹ́lẹ̀ sí ibi mímọ́ Israẹli. Sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ilẹ̀ Israẹli. 3…
Idà OLUWA 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀; ó ní, 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, kọjú sí Jerusalẹmu kí o sọ àsọtẹ́lẹ̀ sí ibi mímọ́ Israẹli. Sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ilẹ̀ Israẹli. 3…
Ìwà Ibi Jerusalẹmu 1 OLUWA tún bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, ṣé o óo dájọ́, ṣé o óo dájọ́ ìlú tí ó kún fún ìpànìyàn yìí?…
Àwọn Arabinrin Tí Wọ́n Jẹ́ Ẹlẹ́ṣẹ̀ 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní, 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, àwọn ọmọbinrin meji kan wà, tí wọ́n jẹ́ ọmọ ìyá kan náà. 3…
Ìkòkò Ìdáná tí Ó Dípẹtà 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀ ní ọjọ́ kẹwaa, oṣù kẹwaa, ọdún kẹsan-an tí a ti wà ní ìgbèkùn, ó ní, 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, sàmì…
Àsọtẹ́lẹ̀ Ibi Nípa Amoni 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, kọjú sí àwọn ará Amoni kí o sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa wọn. 3 Wí fún…
Àsọtẹ́lẹ̀ Ibi Nípa Tire 1 Ní ọjọ́ kinni oṣù, ní ọdún kọkanla tí a dé ìgbèkùn, OLUWA bá mi sọ̀rọ̀: ó ní, 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, nítorí pé àwọn ará…
Orin Arò fún Ìlú Tire 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní, 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, kọ orin arò nípa ìlú Tire. 3 Sọ fún ìlú Tire tí ó wà…
Àsọtẹ́lẹ̀ Ibi Nípa Ọba Tire 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní, 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, sọ fún ọba Tire pé OLUWA ní, ‘Nítorí pé ìgbéraga kún ọkàn rẹ, o…
Àsọtẹ́lẹ̀ Ibi Nípa Ijipti 1 Ní ọjọ́ kejila oṣù kẹwaa ọdún kẹwaa, OLUWA bá mi sọ̀rọ̀; 2 Ó ní, “Ìwọ ọmọ eniyan, kọjú rẹ sí Farao ọba Ijipti, kí o…
OLUWA Yóo Jẹ Ijipti Níyà 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní, 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, sọ àsọtẹ́lẹ̀ kí o sì wí pé, OLUWA Ọlọrun ní, 3 ‘Ẹ sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn…