ISIKIẸLI 31
A Fi Ijipti Wé Igi Kedari 1 Ní ọjọ́ kinni, oṣù kẹta, ọdún kọkanla tí a ti wà ní ìgbèkùn, OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní, 2 “Ìwọ ọmọ eniyan,…
A Fi Ijipti Wé Igi Kedari 1 Ní ọjọ́ kinni, oṣù kẹta, ọdún kọkanla tí a ti wà ní ìgbèkùn, OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní, 2 “Ìwọ ọmọ eniyan,…
A Fi Ọba Ijipti Wé Diragoni 1 Ní ọjọ́ kinni oṣù kejila, ọdún kejila tí a ti wà ní ìgbèkùn, OLUWA bá mi sọ̀rọ̀. 2 Ó ní, “Ìwọ ọmọ eniyan,…
Ọlọrun Fi Isikiẹli Ṣe Aṣọ́de ní Israẹli 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní, 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, bá àwọn eniyan rẹ sọ̀rọ̀. Wí fún wọn pé bí mo bá…
Àwọn Olùṣọ́-Aguntan Israẹli 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní, 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, sọ àsọtẹ́lẹ̀ kí o fi bá àwọn olùṣọ́-aguntan Israẹli wí, fi àsọtẹ́lẹ̀ bá àwọn olórí Israẹli…
Ìyà Tí Ọlọrun óo Fi Jẹ Edomu 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní, 2 “Ìwọ ọmọ eniyan, dojú kọ òkè Seiri, kí o sì fi àsọtẹ́lẹ̀ bá a wí….
Ibukun Ọlọrun Lórí Israẹli 1 OLUWA ní, “Ìwọ ọmọ eniyan, fi àsọtẹ́lẹ̀ bá àwọn òkè Israẹli wí. Sọ pé, ‘Ẹ̀yin òkè Israẹli, ẹ gbọ́ ohun tí OLUWA wí: 2 Àwọn…
Àfonífojì Tí ó kún fún Egungun Gbígbẹ 1 Agbára OLUWA sọ̀kalẹ̀ sára mi, ẹ̀mí rẹ̀ sì gbé mi wá sinu àfonífojì tí ó kún fún egungun. 2 Ó mú mi…
Gogu Gẹ́gẹ́ Bí Ohun Èlò Ọlọrun 1 OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, 2 ó ní: “Ìwọ ọmọ eniyan, kọjú sí Gogu, ní ilẹ̀ Magogu; tí ó jẹ́ olórí Meṣeki ati Tubali,…
A Ṣẹgun Gogu 1 OLUWA Ọlọrun ní, “Ìwọ ọmọ eniyan, fi àsọtẹ́lẹ̀ bá Gogu wí, sọ fún un pé OLUWA Ọlọrun ní: ‘Mo lòdì sí ọ́, ìwọ Gogu, ìwọ tí…
Isikiẹli Lọ sí Jerusalẹmu Lójú Ìran 1 Ní ọjọ́ kẹwaa oṣù kinni, ọdún kẹẹdọgbọn tí a ti wà ní ìgbèkùn, tíí ṣe ọdún kẹrinla tí ogun fọ́ ìlú Jerusalẹmu, agbára…