JẸNẸSISI 21
A Bí Isaaki 1 OLUWA bẹ Sara wò gẹ́gẹ́ bí ó ti wí, ó sì ṣe fún un gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ̀. 2 Sara lóyún, ó sì bí ọmọkunrin kan…
A Bí Isaaki 1 OLUWA bẹ Sara wò gẹ́gẹ́ bí ó ti wí, ó sì ṣe fún un gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ̀. 2 Sara lóyún, ó sì bí ọmọkunrin kan…
Ọlọrun Pàṣẹ fún Abrahamu pé Kí Ó fi Isaaki Rúbọ 1 Lẹ́yìn nǹkan wọnyi, Ọlọrun dán Abrahamu wò, ó ní, “Abrahamu!” Abrahamu dáhùn pé, “Èmi nìyí.” 2 Ọlọrun ní, “Mú…
1 Ọdún mẹtadinlaadoje (127) ni Sara gbé láyé. 2 Ó kú ní Kiriati Ariba, ní Heburoni, ní ilẹ̀ Kenaani, Abrahamu sọkún, ó sì ṣọ̀fọ̀ rẹ̀. 3 Nígbà tí ó yá,…
Wọ́n Gbeyawo fún Isaaki 1 Abrahamu ti darúgbó, Ọlọrun sì ti bukun un ní gbogbo ọ̀nà. 2 Abrahamu sọ fún iranṣẹ rẹ̀ tí ó dàgbà jù ninu ilé rẹ̀, ẹni…
Àwọn Ọmọ Mìíràn Tí Abrahamu Bí 1 Abrahamu fẹ́ aya mìíràn, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ketura. 2 Ketura bí Simirani, Jokiṣani, Medani, Midiani, Iṣibaku ati Ṣua fún un. 3…
Isaaki Gbé ní Gerari 1 Ní àkókò kan, ìyàn ńlá kan mú ní ilẹ̀ náà, yàtọ̀ sí ìyàn tí ó mú ní ìgbà Abrahamu. Isaaki bá tọ Abimeleki ọba àwọn…
Isaaki Súre fún Jakọbu 1 Nígbà tí Isaaki di arúgbó, tí ojú rẹ̀ sì di bàìbàì tóbẹ́ẹ̀ tí kò le ríran mọ́, ó pe Esau àkọ́bí rẹ̀, ó ní, “Ọmọ…
1 Isaaki bá pe Jakọbu, ó súre fún un, ó sì pàṣẹ fún un pé kò gbọdọ̀ fẹ́ ninu àwọn ọmọbinrin ará Kenaani. 2 Ó ní, “Dìde, lọ sí ilé…
Jakọbu Dé sí Ilé Labani 1 Jakọbu tún ń bá ìrìn àjò rẹ̀ lọ, nígbà tí ó ṣe, ó dé ilẹ̀ àwọn ará ìlà oòrùn. 2 Bí ó ti gbójú…
1 Nígbà tí Rakẹli rí i pé òun kò bímọ fún Jakọbu rárá, ó bẹ̀rẹ̀ sí jowú ẹ̀gbọ́n rẹ̀, ó wí fún Jakọbu pé, “Tí o kò bá fẹ́ kí…