JEREMAYA 1
1 Ọ̀rọ̀ Jeremaya, ọmọ Hilikaya, ọ̀kan ninu àwọn alufaa tí ó wà ní Anatoti, ní ilẹ̀ Bẹnjamini nìyí. 2 Nígbà ayé Josaya, ọmọ Amoni, ọba Juda, ní ọdún kẹtala tí…
1 Ọ̀rọ̀ Jeremaya, ọmọ Hilikaya, ọ̀kan ninu àwọn alufaa tí ó wà ní Anatoti, ní ilẹ̀ Bẹnjamini nìyí. 2 Nígbà ayé Josaya, ọmọ Amoni, ọba Juda, ní ọdún kẹtala tí…
Ìtọ́jú Ọlọrun lórí Israẹli 1 OLUWA sọ fún mi pé, 2 “Lọ kéde sí etígbọ̀ọ́ àwọn ará Jerusalẹmu, pé èmi OLUWA ní, mo ranti bí o ti fi ara rẹ…
Israẹli Alaiṣododo 1 OLUWA ní, “Ṣé bí ọkọ bá kọ iyawo rẹ̀ sílẹ̀, tí iyawo náà sì kó jáde nílé ọkọ, tí ó lọ fẹ́ ẹlòmíràn, ṣé ọkọ rẹ̀ àkọ́kọ́…
Ìpè sí Ìrònúpìwàdà 1 OLUWA ní, “Ẹ̀yin ọmọ Israẹli, bí ẹ bá fẹ́ yipada, ọ̀dọ̀ mi ni kí ẹ pada sí. Mo kórìíra ìbọ̀rìṣà; nítorí náà bí ẹ bá jáwọ́…
1 Máa sáré lọ, sáré bọ̀ ní àwọn òpópónà Jerusalẹmu, wò yíká, kí o sì ṣàkíyèsí rẹ̀! Wo àwọn gbàgede rẹ̀, bóyá o óo rí ẹnìkan, tí ó ń ṣe…
Àwọn Ọ̀tá Yí Jerusalẹmu Ká 1 Ẹ̀yin ọmọ Bẹnjamini, ẹ sá àsálà! Ẹ sá kúrò ní Jerusalẹmu. Ẹ fọn fèrè ogun ní Tekoa, kí ẹ ṣe ìkìlọ̀ fún wọn ní…
Jeremaya Waasu ninu Tẹmpili 1 OLUWA rán Jeremaya níṣẹ́, ó ní 2 kí Jeremaya dúró sí ẹnu ọ̀nà ilé OLUWA, kí ó sì kéde pé: “Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ OLUWA, gbogbo…
1 “Tó bá di ìgbà náà, wọn yóo kó egungun àwọn ọba Juda jáde kúrò ninu ibojì wọn, ati egungun àwọn ìjòyè ibẹ̀; ati ti àwọn alufaa, ati ti àwọn…
1 Orí mi ìbá jẹ́ kìkì omi, kí ojú mi sì jẹ́ orísun omijé; tọ̀sán-tòru ni ǹ bá fi máa sọkún, nítorí àwọn eniyan mi tí ogun ti pa. 2…
Ìbọ̀rìṣà ati Ìjọ́sìn Tòótọ́ 1 Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ tí OLUWA ń ba yín sọ, ẹ̀yin ọmọ Israẹli: 2 OLUWA ní, “Ẹ má kọ́ àṣà àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn, ẹ má sì…