JEREMAYA 11

Jeremaya ati Majẹmu 1 OLUWA bá èmi Jeremaya sọ̀rọ̀, 2 ó ní, “Gbọ́ ọ̀rọ̀ majẹmu yìí, kí o sì sọ ọ́ fún àwọn ọmọ Juda, ati àwọn tí ń gbé…

JEREMAYA 12

1 Olódodo ni ọ́, OLUWA, nígbà tí mo bá ń fẹjọ́ sùn ọ́; sibẹ n óo ro ẹjọ́ mi níwájú rẹ. Kí ló dé tí nǹkan ń dára fún àwọn…

JEREMAYA 13

Òwe Aṣọ Funfun 1 OLUWA sọ fún mi pé, “Lọ ra aṣọ funfun kan, kí o lọ́ ọ mọ́ ìdí, má sì tì í bọ omi rárá.” 2 Mo bá…

JEREMAYA 14

Ọ̀gbẹlẹ̀ Ńlá 1 Ọ̀rọ̀ tí OLUWA sọ fún Jeremaya nípa ọ̀gbẹlẹ̀ nìyí: 2 “Juda ń ṣọ̀fọ̀, àwọn ẹnubodè ìlú rẹ̀ wà ninu ìnira. Àwọn eniyan inú rẹ̀ ń sọkún ní…

JEREMAYA 15

Ìparun Yóo Dé Bá Àwọn Ọmọ Juda 1 OLUWA bá tún sọ fún mi pé, “Mose ati Samuẹli ìbáà wá dúró níwájú mi, ọkàn mi kò lè yọ́ sí àwọn…

JEREMAYA 16

Ìfẹ́ OLUWA ní Ìgbésí Ayé Jeremaya 1 OLUWA tún bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: 2 “O kò gbọdọ̀ fẹ́ iyawo tabi kí o bímọ ní ibí yìí. 3 Nítorí ohun…

JEREMAYA 17

Ẹ̀ṣẹ̀ ati Ìjìyà Juda 1 OLUWA ní, “Gègé irin ni a fi kọ ẹ̀ṣẹ̀ Juda sílẹ̀ gègé òkúta dayamọndi ni a sì fi kọ ọ́ sí ọkàn yín, ati sí…

JEREMAYA 18

Jeremaya nílé Amọ̀kòkò 1 OLUWA bá Jeremaya sọ̀rọ̀, ó ní: 2 “Dìde, lọ sí ilé amọ̀kòkò, níbẹ̀ ni óo ti gbọ́ ọ̀rọ̀ tí mo fẹ́ bá ọ sọ.” 3 Mo…

JEREMAYA 19

Ìgò Amọ̀ Tí Ó Fọ́ 1 OLUWA ní kí n lọ ra ìgò amọ̀ kan, kí n mú díẹ̀ ninu àwọn àgbààgbà ìlú ati àwọn bíi mélòó kan ninu àwọn…

JEREMAYA 20

Ìjà láàrin Jeremaya ati Paṣuri Alufaa 1 Nígbà tí Paṣuri alufaa, ọmọ Imeri, tí ó jẹ́ olórí àwọn olùṣọ́ ilé OLUWA, gbọ́ ọ̀rọ̀ tí Jeremaya ń sọ, 2 ó ní…