JEREMAYA 31
Israẹli Pada sílé 1 OLUWA ní, “Àkókò ń bọ̀ tí n óo jẹ́ Ọlọrun gbogbo ìdílé Israẹli, tí àwọn náà yóo sì jẹ́ eniyan mi. 2 Àwọn tí wọ́n bọ́…
Israẹli Pada sílé 1 OLUWA ní, “Àkókò ń bọ̀ tí n óo jẹ́ Ọlọrun gbogbo ìdílé Israẹli, tí àwọn náà yóo sì jẹ́ eniyan mi. 2 Àwọn tí wọ́n bọ́…
Jeremaya Ra Ilẹ̀ 1 OLUWA bá Jeremaya sọ̀rọ̀ ní ọdún kẹwaa tí Sedekaya jọba ní Juda, tí ó jẹ́ ọdún kejidinlogun tí Nebukadinesari jọba. 2 Àwọn ọmọ ogun Babiloni dó…
Ìlérí Ìrètí Mìíràn 1 OLUWA bá Jeremaya sọ̀rọ̀ lẹẹkeji, nígbà tí ó ṣì wà ní ẹ̀wọ̀n, ní àgbàlá àwọn tí ń ṣọ́ ààfin. 2 OLUWA tí ó dá ayé, tí…
Iṣẹ́ tí A Rán sí Sedekaya 1 Ọ̀rọ̀ tí OLUWA bá Jeremaya sọ nìyí, nígbà tí Nebukadinesari, ọba Babiloni, ati gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀, ati gbogbo ìjọba ayé tí…
Jeremaya ati Àwọn Ọmọ Rekabu 1 OLUWA bá Jeremaya sọ̀rọ̀ ní ìgbà ayé Jehoiakimu ọmọ Josaya, ọba Juda; ó ní, 2 “Lọ sí ilé àwọn ọmọ Rekabu kí o bá…
Baruku Ka Àkọsílẹ̀ ninu Ilé OLUWA 1 Ní ọdún kẹrin ìjọba Jehoiakimu ọmọ Josaya ọba Juda, OLUWA sọ fún Jeremaya pé, 2 “Mú ìwé kíká kí o sì kọ gbogbo…
Ohun Tí Sedekaya Bèèrè lọ́wọ́ Jeremaya 1 Nebukadinesari, ọba Babiloni fi Sedekaya, ọmọ Josaya, jọba ní ilẹ̀ Juda dípò Jehoiakini, ọmọ Jehoiakimu. 2 Ṣugbọn Sedekaya ati àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ ati…
Wọ́n Ju Jeremaya sinu Kànga Gbígbẹ 1 Nígbà tí Ṣefataya, ọmọ Matani, ati Gedalaya, ọmọ Paṣuri, ati Jukali, ọmọ Ṣelemaya, ati Paṣuri ọmọ Malikaya gbọ́ ọ̀rọ̀ tí Jeremaya ń sọ…
Ìṣubú Jerusalẹmu 1 Ní oṣù kẹwaa, ọdún kẹsan-an ìjọba Sedekaya, ọba Juda, Nebukadinesari, ọba Babiloni, ati àwọn ọmọ ogun rẹ̀ gbógun ti Jerusalẹmu, wọ́n sì dótì í. 2 Ní ọjọ́…
Jeremaya Ń Gbé Ọ̀dọ̀ Gedalaya 1 OLUWA bá Jeremaya sọ̀rọ̀ lẹ́yìn tí Nebusaradani, olórí àwọn tí ń ṣọ́ ọba Babiloni, tú u sílẹ̀ ní Rama. Nebusaradani rí Jeremaya tí wọ́n…