JEREMAYA 41

1 Ní oṣù keje ni Iṣimaeli, ọmọ Netanaya ọmọ Eliṣama dé, ìdílé ọba ni ó ti wá, ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìjòyè ọba. Òun pẹlu àwọn ọkunrin mẹ́wàá…

JEREMAYA 42

Àwọn Eniyan náà Ní kí Jeremaya Gbadura fún Àwọn 1 Lẹ́yìn náà gbogbo àwọn olórí ogun ati Johanani, ọmọ Karea ati Asaraya, ọmọ Hoṣaaya, ati gbogbo àwọn ará Juda, lọ́mọdé…

JEREMAYA 43

Wọ́n Mú Jeremaya Lọ sí Ijipti 1 Nígbà tí Jeremaya parí gbogbo ọ̀rọ̀ tí OLUWA Ọlọrun wọn rán an sí gbogbo àwọn ará ìlú, 2 Asaraya, ọmọ Hoṣaaya, ati Johanani,…

JEREMAYA 44

Iṣẹ́ Tí OLUWA Rán sí Àwọn Ọmọ Israẹli ní Ijipti 1 Nǹkan tí Jeremaya gbọ́ nípa gbogbo àwọn Juu tí wọn ń gbé Migidoli ati Tapanhesi, ati Memfisi ati ilẹ̀…

JEREMAYA 45

Ìlérí Ọlọrun fún Baruku 1 Ọ̀rọ̀ tí Jeremaya wolii sọ fún Baruku ọmọ Neraya nìyí, ní ọdún kẹrin tí Jehoiakimu, ọmọ Josaya, jọba ní Juda. Baruku ń kọ ohun tí…

JEREMAYA 46

Nebukadinesari ṣẹgun Ijipti ní Kakemiṣi 1 Ọ̀rọ̀ tí OLUWA bá Jeremaya wolii sọ nípa àwọn orílẹ̀-èdè nìyí. 2 Ọ̀rọ̀ lórí Ijipti: Nípa àwọn ọmọ ogun Farao Neko, ọba Ijipti, tí…

JEREMAYA 47

Iṣẹ́ tí OLUWA Rán sí Àwọn Ará Filistia 1 OLUWA bá Jeremaya wolii sọ̀rọ̀ nípa Filistini kí Farao tó ṣẹgun Gasa, 2 Ó ní, “Wò ó, omi kan ń ru…

JEREMAYA 48

Ìparun Moabu 1 OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli sọ nípa Moabu pé, “Nebo gbé nítorí yóo di ahoro! Ojú yóo ti Kiriataimu nítorí ogun óo kó o; ìtìjú yóo…

JEREMAYA 49

Ìdájọ́ OLUWA Lórí Amoni 1 Ohun tí OLUWA sọ nípa àwọn ará Amoni nìyí: Ó ní, “Ṣé Israẹli kò lọ́mọ ni? Tabi kò ní àrólé? Kí ló dé tí àwọn…

JEREMAYA 50

Ogun kó Babiloni 1 OLUWA bá wolii Jeremaya sọ̀rọ̀ nípa Babiloni ní ilẹ̀ àwọn ará Kalidea pé: 2 “Kéde láàrin àwọn orílẹ̀-èdè, ta àsíá, kí o sì kéde. Má fi…