JOBU 1
Satani Dán Jobu Wò 1 Ọkunrin kan wà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jobu; ó ń gbé ilẹ̀ Usi, ó jẹ́ olódodo ati olóòótọ́ eniyan, ó bẹ̀rù Ọlọrun, ó sì…
Satani Dán Jobu Wò 1 Ọkunrin kan wà tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Jobu; ó ń gbé ilẹ̀ Usi, ó jẹ́ olódodo ati olóòótọ́ eniyan, ó bẹ̀rù Ọlọrun, ó sì…
Satani Tún Dán Jobu Wò 1 Nígbà tí ó tún yá tí àwọn ọmọ Ọlọrun wá farahàn níwájú OLUWA, Satani náà wà láàrin wọn. 2 OLUWA tún bi Satani pé,…
Jobu Ráhùn sí Ọlọrun 1 Nígbà tí ó yá, Jobu bẹ̀rẹ̀ sí sọ̀rọ̀, ó fi ọjọ́ ìbí ara rẹ̀ bú. 2 Ó ní: 3 “Ègún ni fún ọjọ́ tí wọ́n…
Ìfọ̀rọ̀wérọ̀ Kinni 1 Nígbà náà ni Elifasi, ará Temani, dá Jobu lóhùn, ó ní: 2 “Bí eniyan bá bá ọ sọ̀rọ̀, ṣé kò ní bí ọ ninu? Àbí eniyan ha…
1 “Pe ẹnìkan nisinsinyii; ǹjẹ́ ẹnikẹ́ni dá ọ lóhùn? Ẹni mímọ́ wo ni o lè tọ̀ lọ? 2 Dájúdájú ibinu a máa pa òmùgọ̀, owú jíjẹ a sì máa pa…
1 Jobu bá dáhùn pé, 2 “Bí ó bá ṣeéṣe láti wọn ìbànújẹ́ mi, tí a bá sì le gbé ìdààmú mi lé orí ìwọ̀n, 3 ìbá wúwo ju yanrìn…
1 “Ìgbésí ayé eniyan le koko, ọjọ́ ayé rẹ̀ sì dàbí ti alágbàṣe. 2 Ó dàbí ẹrú tí ń wá ìbòòji kiri ati bí alágbàṣe tí ń dúró de owó…
1 Bilidadi ará Ṣuha dáhùn pé, 2 “O óo ti sọ irú ọ̀rọ̀ wọnyi pẹ́ tó, tí ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ yóo sì dàbí afẹ́fẹ́ líle? 3 Ṣé Ọlọrun a máa…
1 Jobu dáhùn pé: 2 “Lóòótọ́, mo mọ̀ pé bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ rí, ṣugbọn báwo ni ẹlẹ́ran ara ṣe lè jẹ́ olódodo níwájú Ọlọrun? 3 Bí eniyan tilẹ̀ fẹ́ bá…
1 “Ayé sú mi, nítorí náà n kò ní dákẹ́ ìráhùn; n óo sọ̀rọ̀ pẹlu ìbànújẹ́ ọkàn. 2 N óo sọ fún Ọlọrun pé kí ó má dá mi lẹ́bi;…