JOBU 11

1 Sofari ará Naama dáhùn pé, 2 “Ǹjẹ́ ó dára kí eniyan sọ ọpọlọpọ ọ̀rọ̀ kalẹ̀ báyìí kí ó má sì ìdáhùn? Àbí, ṣé ọ̀pọ̀ ọ̀rọ̀ lè mú kí á…

JOBU 12

1 Jobu dáhùn pé: 2 “Láìsí àní àní, ẹ̀yin ni agbẹnusọ gbogbo eniyan, bí ẹ bá jáde láyé, ọgbọ́n kan kò tún ní sí láyé mọ́. 3 Bí ẹ ti…

JOBU 13

1 “Gbogbo ìwọ̀nyí ni ojú mi ti rí rí, tí etí mi ti gbọ́, tí ó sì yé mi. 2 Ohun tí ẹ mọ̀ wọnyi, èmi náà mọ̀ ọ́n, ẹ…

JOBU 14

1 “Ẹnikẹ́ni tí obinrin bá bí, ọlọ́jọ́ kúkúrú ni, ó sì kún fún ìpọ́njú. 2 Yóo kọ́ yọ bí òdòdó, lẹ́yìn náà yóo sì rẹ̀ dànù. Yóo kọjá lọ bí…

JOBU 15

Ìfọ̀rọ̀wérọ̀ Keji 1 Elifasi ará Temani bá dáhùn pé, 2 “Ṣé ọlọ́gbọ́n a máa fọ èsì tí kò mọ́gbọ́n lọ́wọ́? Kí ó dàbí àgbá òfìfo? 3 Kí ó máa jiyàn…

JOBU 16

1 Jobu bá dáhùn pé, 2 “Èmi náà ti gbọ́ irú nǹkan wọnyi rí, ọlọ́rọ̀ ìtùnú kòbákùngbé ni gbogbo yín. 3 Ǹjẹ́ ọ̀rọ̀ asán tí ẹ̀ ń sọ yìí tilẹ̀…

JOBU 17

1 “Ọkàn mi bàjẹ́, ọjọ́ ayé mi ti dópin, ibojì sì ń dúró dè mí. 2 Dájúdájú àwọn ẹlẹ́yà yí mi káàkiri, wọ́n ń fi mí ṣe yẹ̀yẹ́ lojukooju. 3…

JOBU 18

1 Bilidadi ará Ṣuha bá tún dáhùn pé, 2 “Ìgbàwo ni o óo sinmi ẹjọ́ tí ò ń tò yìí? Ohun tí a tí ń bá ọ sọ ni kí…

JOBU 19

1 Jobu bá dáhùn, ó ní, 2 “Ẹ óo ti ni mí lára pẹ́ tó, tí ẹ óo máa fi ọ̀rọ̀ yín bà mí ninu jẹ́? 3 Ẹ kẹ́gàn mi…

JOBU 20

1 Sofari, ará Naama bá dáhùn pé, 2 “Lọ́kàn mi, mo fẹ́ fèsì sí ọ̀rọ̀ rẹ, ara sì ń wá mi, bí ẹni pé kí n dá ọ lóhùn. 3…