JOBU 21

1 Jobu dáhùn pé, 2 “Ẹ fetí sí ọ̀rọ̀ mi dáradára, kí ẹ sì jẹ́ kí ó jẹ́ ìtùnú fun yín. 3 Ẹ farabalẹ̀, kí ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ mi, lẹ́yìn…

JOBU 22

ÌFỌ̀RỌ̀WÉRỌ̀ KẸTA 1 Elifasi ará Temani bá dáhùn pé, 2 “Ǹjẹ́ eniyan lè wúlò fún Ọlọrun? Nítòótọ́, bí eniyan tilẹ̀ jẹ́ ọlọ́gbọ́n, ara rẹ̀ ni ó wúlò fún. 3 Ǹjẹ́…

JOBU 23

1 Nígbà náà ni Jobu dáhùn pé, 2 “Lónìí, ìráhùn mi tún kún fún ẹ̀dùn, ọwọ́ Ọlọrun ń le lára mi, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé mò ń kérora. 3…

JOBU 24

1 “Kí ló dé tí Olodumare kò fi yan ọjọ́ ìdájọ́, kí àwọn tí wọ́n mọ̀ ọ́n sì rí ọjọ́ náà? 2 “Àwọn eniyan a máa hú òkúta ààlà kúrò,…

JOBU 25

1 Bilidadi ará Ṣuha bá dáhùn pé, 2 “Ọlọrun ni ọba, òun ló sì tó bẹ̀rù, ó ń ṣe àkóso alaafia lọ́run. 3 Ta ló lè ka àwọn ọmọ ogun…

JOBU 26

1 Jobu bá dáhùn pé, 2 “Ìrànlọ́wọ́ wo ni ẹ ti ṣe fún àwọn tí wọn kò lágbára? Aláìlera wo ni ẹ ti gbàlà? 3 Ìmọ̀ràn wo ni ẹ ti…

JOBU 27

1 Jobu tún dáhùn pé, 2 “Mo fi Ọlọrun tí ó gba ẹ̀tọ́ mi búra, mo fi Olodumare tí ó mú kí ọkàn mi bàjẹ́ ṣẹ̀rí, 3 níwọ̀n ìgbà tí…

JOBU 28

Ọ̀rọ̀ Ìyìn Nípa Ọgbọ́n 1 “Dájúdájú, ibìkan wà tí wọ́n ti ń wa fadaka, ibìkan sì wà tí wọ́n ti ń yọ́ wúrà. 2 Inú ilẹ̀ ni a ti ń…

JOBU 29

Ìparí Ọ̀rọ̀ Jobu 1 Jobu tún ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ lọ báyìí pé, 2 “Ìbá jẹ́ tún rí fún mi, bí ìgbà àtijọ́, nígbà tí Ọlọrun ń tọ́jú mi; 3…

JOBU 30

1 “Ṣugbọn nisinsinyii àwọn tí wọ́n kéré sí mi ń fi mí ṣe ẹlẹ́yà, àwọn tí baba wọn kò tó fi wé àwọn ajá tí ń ṣọ́ agbo ẹran mi….