JOBU 31
1 “Mo ti bá ojú mi dá majẹmu; n óo ṣe wá máa wo wundia? 2 Kí ni yóo jẹ́ ìpín mi lọ́dọ̀ Ọlọrun lókè? Kí ni ogún mi lọ́dọ̀…
1 “Mo ti bá ojú mi dá majẹmu; n óo ṣe wá máa wo wundia? 2 Kí ni yóo jẹ́ ìpín mi lọ́dọ̀ Ọlọrun lókè? Kí ni ogún mi lọ́dọ̀…
Ọ̀rọ̀ Elihu 1 Àwọn ọkunrin mẹtẹẹta náà kò dá Jobu lóhùn mọ́, nítorí pé ó jẹ́ olódodo lójú ara rẹ̀. 2 Elihu, ọmọ Barakeli, ará Busi, ní ìdílé Ramu bá…
1 “Jobu, tẹ́tí sílẹ̀ nisinsinyii kí o gbọ́ ọ̀rọ̀ mi. 2 Wò ó! Mo fẹ́ bẹ̀rẹ̀ sí sọ̀rọ̀, ọ̀rọ̀ sì pọ̀ tí mo fẹ́ sọ. 3 Òtítọ́ inú ni mo…
1 Elihu tún ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ bọ̀, ó ní, 2 “Ẹ gbọ́rọ̀ mi, ẹ̀yin ọlọ́gbọ́n, ẹ tẹ́tí sí mi, ẹ̀yin tí ẹ ní ìmọ̀, 3 nítorí bí ahọ́n ti…
1 Elihu tún ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ bọ̀, ó ní, 2 “Jobu, ṣé o rò pé ó tọ̀nà, kí o máa sọ pé, ‘Ọ̀nà mi tọ́ níwájú Ọlọrun?’ 3 Kí…
1 Elihu tún tẹ̀síwájú ninu ọ̀rọ̀ rẹ̀, ó ní, 2 “Ní sùúrù fún mi díẹ̀, n óo ṣe àlàyé fún ọ, nítorí mo ní ohun kan tí mo fẹ́ gbẹnusọ…
1 “Nígbà tí mo gbọ́, ọkàn mi wárìrì, ó sì fò sókè ní ipò rẹ̀. 2 Gbọ́ ohùn rẹ̀ tí ń dún bí ààrá, ati ariwo tí ń ti ẹnu…
OLUWA dá Jobu Lóhùn 1 Nígbà náà ni OLUWA dá Jobu lóhùn láti inú ìjì líle. 2 Ó bi í pé, “Ta ni ẹni tí ń bu ẹnu àtẹ́ lu…
1 “Ǹjẹ́ o mọ ìgbà tí àwọn ewúrẹ́ orí àpáta ń bímọ? Ṣé o ti ká àgbọ̀nrín mọ́ ibi tí ó ti ń bímọ rí? 2 Ǹjẹ́ o lè ka…
1 OLUWA tún sọ fún Jobu pé, 2 “Ṣé ẹni tí ń bá eniyan rojọ́ lè bá Olodumare rojọ́? Kí ẹni tí ń bá Ọlọrun jiyàn dáhùn.” 3 Nígbà náà…