JOHANU 1

Ọlọrun di Eniyan 1 Ní ìbẹ̀rẹ̀, kí á tó dá ayé, ni Ọ̀rọ̀ ti wà, Ọ̀rọ̀ wà pẹlu Ọlọrun, Ọlọrun sì ni Ọ̀rọ̀ náà. 2 Òun ni ó wà pẹlu…

JOHANU 2

Jesu Lọ sí Ibi Igbeyawo Kan ní Kana 1 Ní ọjọ́ kẹta, wọ́n ń ṣe igbeyawo kan ní Kana, ìlú kan ní Galili. Ìyá Jesu wà níbẹ̀. 2 Wọ́n pe…

JOHANU 3

Jesu ati Nikodemu 1 Ọkunrin kan wà ninu àwọn Farisi tí ń jẹ́ Nikodemu. Ó jẹ́ ọ̀kan ninu ìgbìmọ̀ àwọn Juu. 2 Ọkunrin yìí fi òru bojú lọ sọ́dọ̀ Jesu….

JOHANU 4

Jesu Bá Obinrin Ará Samaria Sọ̀rọ̀ 1 Àwọn Farisi gbọ́ pé àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu ń pọ̀ ju àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Johanu lọ; ati pé Jesu ń ṣe ìrìbọmi fún ọpọlọpọ eniyan…

JOHANU 5

Jesu wo Arọ kan Sàn ní Jerusalẹmu 1 Lẹ́yìn èyí, ó tó àkókò fún ọ̀kan ninu àjọ̀dún àwọn Juu: Jesu bá lọ sí Jerusalẹmu. 2 Ẹnu ọ̀nà kan wà ní…

JOHANU 6

Jesu Bọ́ Ẹgbẹẹdọgbọn (5,000) Eniyan 1 Lẹ́yìn èyí, Jesu lọ sí òdìkejì òkun Galili tí ó tún ń jẹ́ òkun Tiberiasi. 2 Ọ̀pọ̀ eniyan ń tẹ̀lé e nítorí wọ́n rí…

JOHANU 7

Àwọn Arakunrin Jesu kò gbà á gbọ́ 1 Lẹ́yìn èyí, Jesu ń lọ káàkiri ní ilẹ̀ Galili nítorí kò fẹ́ máa káàkiri ilẹ̀ Judia mọ́, nítorí àwọn Juu ń wá…

JOHANU 8

Ìtàn Obinrin tí Ó Ṣe Àgbèrè [ 1 Ni olukuluku wọn bá lọ sí ilé wọn; ṣugbọn Jesu lọ sí Òkè Olifi. 2 Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, ó tún lọ…

JOHANU 9

Jesu Wo Ẹni tí Wọ́n Bí Ní Afọ́jú Sàn 1 Bí Jesu ti ń kọjá lọ, ó rí ọkunrin kan tí ó fọ́jú láti inú ìyá rẹ̀ wá. 2 Àwọn…

JOHANU 10

Jesu Fi Aguntan Ṣe Àkàwé 1 “Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ dájúdájú pé ẹni tí kò bá gba ẹnu-ọ̀nà wọ àgbàlá ilé tí àwọn aguntan ń sùn sí, ṣugbọn tí…