JOHANU 11

Ikú Lasaru 1 Ọkunrin kan tí ń jẹ́ Lasaru ń ṣàìsàn. Ní Bẹtani ni ó ń gbé, ní ìlú kan náà pẹlu Maria ati Mata arabinrin rẹ̀. 2 Maria yìí…

JOHANU 12

Maria Tú Òróró Dà Sára Jesu ní Bẹtani 1 Nígbà tí Àjọ̀dún Ìrékọjá ku ọjọ́ mẹfa, Jesu lọ sí Bẹtani níbi tí Lasaru wà, ẹni tí ó kú, tí Jesu…

JOHANU 13

Jesu Wẹ Ẹsẹ̀ Àwọn Ọmọ-ẹ̀yìn Rẹ̀ 1 Nígbà tí àkókò Àjọ̀dún Ìrékọjá ku ọjọ́ kan, Jesu mọ̀ pé àkókò tó, tí òun yóo kúrò láyé yìí lọ sọ́dọ̀ Baba. Fífẹ́…

JOHANU 14

Jesu Ni Ọ̀nà Dé Ọ̀dọ̀ Baba 1 “Ẹ má ṣe jẹ́ kí ọkàn yín dàrú. Ẹ gba Ọlọrun gbọ́, kí ẹ sì gba èmi náà gbọ́. 2 Yàrá pupọ ni…

JOHANU 15

Jesu Ni Igi Àjàrà 1 “Èmi ni àjàrà tòótọ́. Baba mi ni àgbẹ̀ tí ń mójútó ọgbà àjàrà. 2 Gígé ni yóo gé gbogbo ẹ̀ka ara mi tí kò bá…

JOHANU 16

1 “Mo sọ gbogbo nǹkan yìí fun yín kí igbagbọ yín má baà yẹ̀. 2 Wọn yóo le yín jáde kúrò ninu ilé ìpàdé wọn. Èyí nìkan kọ́, àkókò ń…

JOHANU 17

Adura Jesu 1 Lẹ́yìn tí Jesu ti sọ ọ̀rọ̀ wọnyi tán, ó gbé ojú sókè ọ̀run, ó ní, “Baba, àkókò náà dé! Jẹ́ kí ògo rẹ hàn lára Ọmọ, kí…

JOHANU 18

Àwọn Ọ̀tá Mú Jesu 1 Lẹ́yìn tí Jesu ti gba adura yìí tán, òun ati àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ jáde lọ sí òdìkejì àfonífojì odò Kidironi. Ọgbà kan wà níbẹ̀. Ó…

JOHANU 19

1 Nígbà náà ni Pilatu mú Jesu, ó ní kí wọ́n nà án. 2 Àwọn ọmọ-ogun bá fi ìtàkùn ẹlẹ́gùn-ún hun adé, wọ́n fi dé e lórí; wọn wọ̀ ọ́…

JOHANU 20

Ajinde Jesu 1 Ní kutukutu ọjọ́ kinni ọ̀sẹ̀, kí ilẹ̀ tó mọ́, Maria Magidaleni lọ sí ibojì náà, ó rí i pé wọ́n ti yí òkúta kúrò lẹ́nu rẹ̀. 2…