JOHANU 21

Jesu Fara Han Àwọn Ọmọ-Ẹ̀yìn Meje 1 Lẹ́yìn èyí, Jesu tún fara han àwọn ọmọ-ẹ̀yìn ní òkun Tiberiasi. Bí ó ṣe farahàn wọ́n nìyí: 2 Simoni Peteru, ati Tomasi tí…