JONA 1

Jona Ṣe Àìgbọràn sí OLUWA 1 OLUWA bá Jona ọmọ Amitai sọ̀rọ̀, ó ní, 2 “Dìde, lọ sí Ninefe, ìlú ńlá nì, kéde, kí o sì kìlọ̀ fún wọn pé…

JONA 2

Adura Jona 1 Jona gbadura sí OLUWA Ọlọrun rẹ̀ láti inú ẹja náà, 2 ó ní, “Ninu ìpọ́njú mi, mo ké pe OLUWA, ó sì dá mi lóhùn, mo ké…

JONA 3

Jona Gbọ́ràn sí OLUWA Lẹ́nu 1 OLUWA tún bá Jona sọ̀rọ̀ nígbà keji, ó ní: 2 “Dìde, lọ sí Ninefe, ìlú ńlá nì, kí o sì kéde iṣẹ́ tí mo…

JONA 4

Ibinu Jona ati Àánú Ọlọrun 1 Ṣugbọn bí Ọlọrun ti ṣe yìí kò dùn mọ́ Jona ninu rárá, inú bí i. 2 Ó bá gbadura sí OLUWA, ó ní: “OLUWA,…