KỌRINTI KEJI 1

Ìkíni 1 Èmi Paulu, aposteli Kristi Jesu nípasẹ̀ ìfẹ́ Ọlọrun, ati Timoti, arakunrin wa, ni à ń kọ ìwé yìí sí Ìjọ Ọlọrun tí ó wà ní Kọrinti ati sí…

KỌRINTI KEJI 2

1 Nítorí náà, mo pinnu pé n kò tún fẹ́ kí wíwá tí mo bá wá sọ́dọ̀ yín jẹ́ ti ìbànújẹ́ mọ́. 2 Bí mo bá bà yín ninu jẹ́,…

KỌRINTI KEJI 3

Òjíṣẹ́ Majẹmu Titun 1 Ṣé a óo ṣẹ̀ṣẹ̀ tún bẹ̀rẹ̀ láti máa ṣe àpèjúwe ara wa ni; àbí a nílò láti mú ìwé ẹ̀rí tọ̀ yín wá tí yóo sọ…

KỌRINTI KEJI 4

Ìṣúra ti Ẹ̀mí ninu ìkòkò Amọ̀ 1 Nítorí èyí, níwọ̀n ìgbà tí ó wu Ọlọrun ninu àánú rẹ̀ láti fi iṣẹ́ yìí fún wa ṣe, ọkàn wa kò rẹ̀wẹ̀sì. 2…

KỌRINTI KEJI 5

1 Nítorí a mọ̀ pé bí àgọ́ ara tí a fi ṣe ilé ní ayé yìí bá wó, a ní ilé kan lọ́dọ̀ Ọlọrun, tí a kò fi ọwọ́ kọ́,…

KỌRINTI KEJI 6

1 Gẹ́gẹ́ bí alábàáṣiṣẹ́pọ̀, à ń bẹ̀ yín pé kí ẹ má ṣe jẹ́ kí gbígbà tí ẹ gba oore-ọ̀fẹ́ Ọlọrun jẹ́ lásán. 2 Nítorí Ọlọrun sọ pé, “Mo gbọ́…

KỌRINTI KEJI 7

1 Nítorí náà, ẹ̀yin àyànfẹ́, nígbà tí ẹ ti ní àwọn ìlérí yìí, ẹ wẹ gbogbo ìdọ̀tí kúrò ní ara ati ẹ̀mí yín. Ẹ ya ara yín sí mímọ́ patapata…

KỌRINTI KEJI 8

Àwọn Onigbagbọ Ará Masedonia Lawọ́ 1 Ẹ̀yin ará, a fẹ́ kí ẹ mọ ohun tí oore-ọ̀fẹ́ Ọlọrun ti ṣe láàrin àwọn ìjọ Masedonia. 2 Wọ́n ní ọpọlọpọ ìdánwò nípa ìpọ́njú….

KỌRINTI KEJI 9

Ọrẹ fún Àwọn Onigbagbọ 1 Nípa ti ìrànlọ́wọ́ fún àwọn onigbagbọ, kò nílò pé kí n tún kọ ìwé si yín mọ́. 2 Nítorí mo mọ àníyàn yín, mo sì…

KỌRINTI KEJI 10

Paulu Gbèjà Ara Rẹ̀ 1 Èmi Paulu fi ìrẹ̀lẹ̀ Kristi ati àánú rẹ̀ bẹ̀ yín, èmi tí ẹ̀ ń sọ pé nígbà tí mo bá wà lọ́dọ̀ yín mo jẹ́…