KỌRINTI KEJI 11

Paulu ati Àwọn Aposteli Èké 1 Ẹ jọ̀wọ́, ẹ gbà mí láyè kí n sọ̀rọ̀ díẹ̀ bí aṣiwèrè. Ẹ gbà mí láyè. 2 Mò ń jowú nítorí yín, bí Ọlọrun…

KỌRINTI KEJI 12

Àwọn Ìran Tí Paulu Rí 1 Ó yẹ kí n fọ́nnu. Rere kan kò ti ibẹ̀ wá, sibẹ n óo sọ ti ìran ati ìfarahàn Oluwa. 2 Mo mọ ọkunrin…

KỌRINTI KEJI 13

Ìkìlọ̀ Ìgbẹ̀yìn 1 Ẹẹkẹta nìyí tí n óo wá sọ́dọ̀ yín. Lẹ́nu ẹlẹ́rìí meji tabi mẹta ni a óo sì ti mọ òtítọ́ gbogbo ọ̀rọ̀. 2 Gẹ́gẹ́ bí mo ti…