KỌRINTI KINNI 11

1 Ẹ máa fara wé mi bí èmi náà tí ń fara wé Kristi. Obinrin Níláti Bo Orí ninu Ìsìn 2 Mo yìn yín nítorí pé ẹ̀ ń ranti mi…

KỌRINTI KINNI 12

Àwọn Ẹ̀bùn Ẹ̀mí Mímọ́ 1 Ẹ̀yin ará, n kò fẹ́ kí nǹkan nípa ẹ̀bùn Ẹ̀mí Mímọ́ ṣókùnkùn si yín. 2 Ẹ mọ̀ pé nígbà tí ẹ jẹ́ aláìmọ Ọlọrun, ẹ̀…

KỌRINTI KINNI 13

Ìfẹ́ 1 Ǹ báà lè sọ oríṣìíríṣìí èdè tí eniyan ń fọ̀, kódà kí n tún lè sọ ti àwọn angẹli, bí n kò bá ní ìfẹ́, bí idẹ tí…

KỌRINTI KINNI 14

Ẹ̀bùn Èdè Àjèjì ati Ti Ìsọtẹ́lẹ̀ 1 Ẹ máa lépa ìfẹ́. Ṣugbọn ẹ tún máa tiraka láti ní Ẹ̀mí Mímọ́, pàápàá jùlọ, ẹ̀bùn ìsọtẹ́lẹ̀. 2 Nítorí ẹni tí ó bá…

KỌRINTI KINNI 15

Ajinde Kristi 1 Ará, mo fẹ́ ran yín létí ọ̀rọ̀ ìyìn rere tí mo fi waasu fun yín, tí ẹ gbà, tí ẹ sì bá dúró. 2 Nípa ìyìn rere…

KỌRINTI KINNI 16

Ìtọrẹ Onigbagbọ 1 Nípa ti ìtọrẹ tí ẹ̀ ń ṣe fún àwọn eniyan Ọlọrun, bí mo ti ṣe ètò pẹlu àwọn ìjọ Galatia, bẹ́ẹ̀ gan-an ni kí ẹ̀yin náà máa…