KRONIKA KEJI 31

Hesekaya Ṣe Àtúnṣe Ẹ̀sìn 1 Nígbà tí wọ́n parí ayẹyẹ wọnyi, gbogbo àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n wá síbi àjọ náà lọ sí àwọn ìlú Juda, wọ́n fọ́ gbogbo òpó…

KRONIKA KEJI 32

Asiria Halẹ̀ Mọ́ Jerusalẹmu 1 Lẹ́yìn gbogbo nǹkan tí Hesekaya ṣe, tí ó sin OLUWA pẹlu òtítọ́, Senakeribu ọba Asiria wá gbógun ti Juda. Ó dó ti àwọn ìlú olódi…

KRONIKA KEJI 33

Manase, Ọba Juda 1 Ọmọ ọdún mejila ni Manase nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún marundinlọgọta. 2 Ó ṣe nǹkan burúkú lójú OLUWA….

KRONIKA KEJI 34

Josaya, Ọba Juda 1 Ọmọ ọdún mẹjọ ni Josaya nígbà tí ó jọba, ó sì wà lórí oyè ní Jerusalẹmu fún ọdún mọkanlelọgbọn. 2 Ó ṣe ohun tí ó dára…

KRONIKA KEJI 35

Josaya Pa Àjọ Ìrékọjá Mọ́ 1 Josaya ṣe Àjọ Ìrékọjá fún OLUWA ní Jerusalẹmu. Ní ọjọ́ kẹrinla, oṣù kinni ni wọ́n pa ọ̀dọ́ aguntan Àjọ Ìrékọjá. 2 Ó yan àwọn…

KRONIKA KEJI 36

Joahasi, ọba Juda 1 Àwọn ọmọ ilẹ̀ Juda bá fi Joahasi, ọmọ Josaya, jọba ní Jerusalẹmu lẹ́yìn baba rẹ̀. 2 Joahasi jẹ́ ẹni ọdún mẹtalelogun nígbà tí ó jọba, ó…