LEFITIKU 1

Àwọn Ẹbọ Tí A Sun Lódidi 1 OLUWA pe Mose, ó sì bá a sọ̀rọ̀ láti inú Àgọ́ Àjọ ó ní, 2 “Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, nígbà tí…

LEFITIKU 2

Ẹbọ Ohun Jíjẹ 1 “Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ mú ọkà wá siwaju OLUWA láti fi rúbọ, ó gbọdọ̀ jẹ́ ìyẹ̀fun dáradára, kí ó da òróró ati turari sórí rẹ̀. 2…

LEFITIKU 3

Ẹbọ Alaafia 1 “Bí ẹnìkan bá fẹ́ rú ẹbọ alaafia, tí ó sì mú ẹran láti inú agbo ẹran rẹ̀ fún ẹbọ náà, kì báà jẹ́ akọ tabi abo, ó…

LEFITIKU 4

Ẹbọ fún Ẹ̀ṣẹ̀ Tí Eniyan Bá Ṣèèṣì Dá 1 OLUWA ní kí Mose 2 sọ fún àwọn eniyan Israẹli pé, bí ẹnikẹ́ni bá ṣèèṣì ṣe ọ̀kankan ninu ohun tí OLUWA…

LEFITIKU 5

Àwọn Ẹ̀ṣẹ̀ Tí Ó Nílò Ẹbọ Ìmúkúrò Ẹ̀ṣẹ̀ 1 “Bí ẹnìkan bá dẹ́ṣẹ̀, nípa pé ó gbọ́ tí wọn ń kéde láàrin àwùjọ pé, kí ẹnikẹ́ni tí ó bá mọ̀…

LEFITIKU 6

1 OLUWA sọ fún Mose, pé, 2 “Bí ẹnikẹ́ni bá dẹ́ṣẹ̀ sí OLUWA nípa ṣíṣe èyíkéyìí ninu nǹkan wọnyi: kì báà jẹ́ pé ó kọ̀ láti dá ohun tí aládùúgbò…

LEFITIKU 7

Ẹbọ Ìmúkúrò Ẹ̀bi 1 “Èyí ni òfin ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀bi. 2 Ó jẹ́ mímọ́ jùlọ; níbi tí wọ́n ti pa ẹran ẹbọ sísun ni wọ́n gbọdọ̀ ti pa ti ẹbọ…

LEFITIKU 8

Ìyàsímímọ́ Aaroni ati Àwọn Ọmọ Rẹ̀ 1 OLUWA sọ fún Mose pé, 2 “Mú Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀ ọkunrin ati ẹ̀wù iṣẹ́ alufaa wọn, ati òróró ìyàsímímọ́, ati akọ…

LEFITIKU 9

Aaroni Rúbọ sí OLUWA 1 Ní ọjọ́ kẹjọ, Mose pe Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀ ati àwọn àgbààgbà Israẹli; 2 ó wí fún Aaroni pé, “Mú ọ̀dọ́ akọ mààlúù kan…

LEFITIKU 10

Ẹ̀ṣẹ̀ Nadabu ati Abihu 1 Àwọn ọmọ Aaroni meji kan, ọkunrin, tí wọn ń jẹ́ Nadabu ati Abihu, mú àwo turari wọn, olukuluku fọn ẹ̀yinná sinu tirẹ̀, wọ́n da turari…