LEFITIKU 21
Àwọn Alufaa Gbọdọ̀ Jẹ́ Mímọ́ 1 OLUWA sọ fún Mose pé kí ó sọ fún àwọn alufaa, àwọn ọmọ Aaroni pé, “Ẹnikẹ́ni ninu wọn kò gbọdọ̀ sọ ara rẹ̀ di…
Àwọn Alufaa Gbọdọ̀ Jẹ́ Mímọ́ 1 OLUWA sọ fún Mose pé kí ó sọ fún àwọn alufaa, àwọn ọmọ Aaroni pé, “Ẹnikẹ́ni ninu wọn kò gbọdọ̀ sọ ara rẹ̀ di…
Àwọn Ohun Ìrúbọ Gbọdọ̀ Jẹ́ Mímọ́ 1 OLUWA rán Mose pé, 2 “Sọ fún Aaroni ati àwọn ọmọkunrin rẹ̀ pé, kí wọ́n máa fi tọ̀wọ̀tọ̀wọ̀ lo àwọn nǹkan mímọ́ tí…
Àwọn Àjọ̀dún Ẹ̀sìn 1 OLUWA sọ fún Mose 2 pé kí ó sọ fún àwọn eniyan Israẹli pé, “Àwọn àjọ̀dún tí èmi OLUWA yàn tí ó gbọdọ̀ kéde gẹ́gẹ́ bí…
Ìtọ́jú Àwọn Fìtílà 1 OLUWA sọ fún Mose pé, 2 “Pàṣẹ fún àwọn eniyan Israẹli pé kí wọn mú ojúlówó òróró olifi wá fún àtùpà ilé mímọ́ mi, kí ó…
Ọdún Keje 1 OLUWA bá Mose sọ̀rọ̀ lórí òkè Sinai, ó ní, 2 “Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, nígbà tí ẹ bá dé ilẹ̀ tí n óo fun yín,…
Ibukun fún Ìgbọràn 1 “Ẹ kò gbọdọ̀ ṣe oriṣa-koriṣa kan fún ara yín, tabi kí ẹ gbé ère gbígbẹ́ kalẹ̀, tabi kí ẹ ri ọ̀wọ̀n òkúta gbígbẹ́ mọ́lẹ̀, kí ẹ…
Àwọn Òfin tí Ó Jẹmọ́ Ohun tí a fi fún OLUWA 1 OLUWA sọ fun Mose 2 pé kí ó sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, “Bí ẹnìkan bá jẹ́jẹ̀ẹ́…