LUKU 1
Ọ̀rọ̀ Iṣaaju sí Tiofilu 1 Ọpọlọpọ eniyan ni wọ́n ti kọ ìròyìn lẹ́sẹẹsẹ, nípa ohun tí ó ti ṣẹlẹ̀ láàrin wa; 2 àwọn tí nǹkan wọnyi ṣojú wọn, tí wọ́n…
Ọ̀rọ̀ Iṣaaju sí Tiofilu 1 Ọpọlọpọ eniyan ni wọ́n ti kọ ìròyìn lẹ́sẹẹsẹ, nípa ohun tí ó ti ṣẹlẹ̀ láàrin wa; 2 àwọn tí nǹkan wọnyi ṣojú wọn, tí wọ́n…
Ìbí Jesu 1 Ní àkókò náà, àṣẹ kan jáde láti ọ̀dọ̀ Kesari Augustu pé kí gbogbo ayé lọ kọ orúkọ wọn sinu ìwé ìjọba. 2 Èyí ni àkọsílẹ̀ ekinni tí…
Iwaasu Johanu Onítẹ̀bọmi 1 Ní ọdún kẹẹdogun tí Ọba Tiberiu ti wà lórí oyè, nígbà tí Pọntiu Pilatu jẹ́ gomina Judia, tí Hẹrọdu jẹ́ baálẹ̀ Galili, tí Filipi arakunrin rẹ̀…
Ìdánwò Jesu 1 Jesu pada láti odò Jọdani, ó kún fún Ẹ̀mí Mímọ́. Ẹ̀mí bá darí rẹ̀ lọ sí aṣálẹ̀. 2 Ogoji ọjọ́ ni èṣù fi dán an wò. Kò…
Jesu Pe Àwọn Ọmọ-Ẹ̀yìn Rẹ̀ Àkọ́kọ́ 1 Ní àkókò kan, bí Jesu ti dúró létí òkun Genesarẹti, ọ̀pọ̀ eniyan péjọ sọ́dọ̀ rẹ̀ láti gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọrun. 2 Ó rí àwọn…
Àwọn Ọmọ-Ẹ̀yìn Jesu Ń Já Ọkà Ní Ọjọ́ Ìsinmi 1 Ní Ọjọ́ Ìsinmi kan, bí Jesu ti ń la oko ọkà kan kọjá, àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí já ọkà,…
Jesu Wo Iranṣẹ Ọ̀gágun Kan Sàn 1 Nígbà tí Jesu parí ọ̀rọ̀ tí ó ń bá àwọn eniyan sọ, ó wọ inú ìlú Kapanaumu lọ. 2 Ọ̀gágun kan ní ẹrú…
Àwọn Obinrin Tí Wọn Ń Ran Jesu Lọ́wọ́ 1 Lẹ́yìn èyí, Jesu ń rìn káàkiri láti ìlú dé ìlú, ati láti abúlé dé abúlé. Ó ń waasu ìyìn rere ìjọba…
Iṣẹ́ Tí Jesu Fi Rán Àwọn Ọmọ-Ẹ̀yìn Mejila 1 Jesu pe àwọn mejila jọ. Ó fún wọn ní agbára ati àṣẹ láti lé gbogbo ẹ̀mí èṣù jáde ati láti ṣe…
Jesu Rán Àwọn Mejilelaadọrin Níṣẹ́ 1 Lẹ́yìn èyí, Oluwa yan àwọn mejilelaadọrin mìíràn, ó rán wọn ní meji-meji ṣiwaju rẹ̀ lọ sí gbogbo ìlú ati ibi tí òun náà fẹ́…