MAKU 1

Iwaasu Johanu Onítẹ̀bọmi 1 Bí ìyìn rere Jesu Kristi Ọmọ Ọlọrun ṣe bẹ̀rẹ̀ nìyí: 2 Gẹ́gẹ́ bí wolii Aisaya ti kọ ọ́ tẹ́lẹ̀ ni ó rí: “Ọlọrun ní, ‘Wò ó!…

MAKU 2

Jesu Wo Arọ Sàn 1 Lẹ́yìn ọjọ́ díẹ̀, Jesu tún lọ sí Kapanaumu, àwọn eniyan gbọ́ pé ó wà ninu ilé kan. 2 Ọ̀pọ̀ eniyan bá wá péjọ sibẹ, wọ́n…

MAKU 3

Ọkunrin Tí Ọwọ́ Rẹ̀ Rọ 1 Jesu tún wọ inú ilé ìpàdé lọ. Ọkunrin kan wà níbẹ̀ tí ọwọ́ rẹ̀ kan rọ. 2 Àwọn kan wà tí wọn ń ṣọ́…

MAKU 4

Òwe Nípa Afunrugbin 1 Jesu tún bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ àwọn eniyan lẹ́bàá òkun. Ogunlọ́gọ̀ eniyan péjọ pọ̀ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí ó fi níláti bọ́ sin ọkọ̀ ojú omi…

MAKU 5

Jesu Mú Wèrè, Ará Geraseni, Lára dá 1 Jesu lọ sí òdìkejì òkun ní ilẹ̀ àwọn ará Geraseni. 2 Bí ó ti jáde kúrò ninu ọkọ̀, ọkunrin wèrè kan wá…

MAKU 6

A Kọ Jesu ní Nasarẹti 1 Jesu jáde kúrò níbẹ̀, ó lọ sí ìlú rẹ̀. Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ bá a lọ. 2 Nígbà tí ó di Ọjọ́ Ìsinmi, ó bẹ̀rẹ̀…

MAKU 7

Àṣà Ìbílẹ̀ 1 Àwọn Farisi ati àwọn amòfin kan tí wọ́n wá láti Jerusalẹmu péjọ sí ọ̀dọ̀ Jesu. 2 Wọ́n rí ninu àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ tí wọn ń fi ọwọ́…

MAKU 8

1 Ní ọjọ́ kan, nígbà tí ọpọlọpọ eniyan tún wà lọ́dọ̀ Jesu, tí wọn kò rí nǹkan jẹ, ó pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, ó wí fún wọn pé, 2 “Àánú…

MAKU 9

1 Ó tún wí fún wọn pé, “Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ dájúdájú pé, àwọn kan wà ninu àwọn tí ó dúró níhìn-ín tí wọn kò ní kú títí wọn…

MAKU 10

Ẹ̀kọ́ Nípa Ipò Ọkọ ati Aya sí Ara Wọn 1 Nígbà tí Jesu dìde kúrò níbẹ̀, ó lọ sí agbègbè Judia, ó rékọjá sí òdìkejì odò Jọdani. Ọpọlọpọ àwọn eniyan…