MIKA 1

1 Ọ̀rọ̀ tí OLUWA sọ fún Mika, ará Moreṣeti nípa Jerusalẹmu ati Samaria nìyí, ní àkókò ìjọba Jotamu, ati ti Ahasi ati ti Hesekaya, àwọn ọba Juda. Ìpohùnréré Ẹkún nítorí…

MIKA 2

Ìjìyà fún Àwọn Tí Wọn ń Ni Àwọn Talaka Lára 1 Ègbé ni fún àwọn tí wọn ń gbìmọ̀ ìkà, tí wọ́n sì ń gbèrò ibi lórí ibùsùn wọn. Nígbà…

MIKA 3

Mika Bá Àwọn Olórí Israẹli Wí 1 Ẹ gbọ́, ẹ̀yin olórí ilé Jakọbu, ati ẹ̀yin alákòóso ilé Israẹli! Ṣé kò yẹ kí ẹ mọ̀ nípa ìdájọ́ òtítọ́? 2 Ẹ̀yin tí…

MIKA 4

Ìjọba Alaafia OLUWA Tí Ó Kárí Ayé 1 Nígbà tí ó bá yá, a óo fìdí òkè ilé OLUWA múlẹ̀ bí òkè tí ó ga jùlọ, a óo gbé e…

MIKA 5

1 Nisinsinyii, a ti fi odi yi yín ká, ogun sì ti dótì wá; wọ́n fi ọ̀pá na olórí Israẹli ní ẹ̀rẹ̀kẹ́. Ọlọrun Ṣèlérí láti Yan Olórí ní Bẹtilẹhẹmu 2…

MIKA 6

Ọlọrun bá Israẹli Rojọ́ 1 Ẹ gbọ́ ohun tí Ọlọrun sọ: Ẹ dìde, kí ẹ ro ẹjọ́ yín níwájú àwọn òkè ńlá, kí ẹ sì jẹ́ kí àwọn òkè kéékèèké…

MIKA 7

Ìwà Ìbàjẹ́ Israẹli 1 Mo gbé! Nítorí pé, mo dàbí ìgbà tí wọn ti kórè èso àkókò ẹ̀ẹ̀rùn tán, tí wọ́n ti ká èso àjàrà tán; tí kò sí èso…