NEHEMAYA 1

1 Ìtàn Nehemaya ọmọ Hakalaya. Ẹ̀dùn Ọkàn Nehemaya fún Jerusalẹmu Ní oṣù Kisilefi, ní ogún ọdún tí Atasasesi jọba ní ilẹ̀ Pasia, mo wà ní Susa tíí ṣe olú-ìlú ilẹ̀…

NEHEMAYA 2

Nehemaya lọ sí Jerusalẹmu 1 Ní oṣù Nisani, ní ogún ọdún tí Atasasesi ọba gorí oyè, mo gbé ọtí waini tí ó wà níwájú rẹ̀ fún un. N kò fajúro…

NEHEMAYA 3

Títún Ògiri Jerusalẹmu Mọ 1 Eliaṣibu, Olórí alufaa, ati àwọn arakunrin rẹ̀ tí àwọn náà jẹ́ alufaa bíi rẹ̀ múra, wọ́n sì kọ́ Ẹnubodè Aguntan. Wọ́n yà á sí mímọ́…

NEHEMAYA 4

Nehemaya Borí Ìṣòro Tí ó Dojú Kọ Iṣẹ́ Rẹ̀ 1 Nígbà tí Sanbalati gbọ́ pé a ti ń kọ́ odi náà, inú bíi gidigidi, ó bá bẹ̀rẹ̀ sí bu ẹnu…

NEHEMAYA 5

Níni Àwọn Talaka Lára 1 Ọpọlọpọ àwọn eniyan náà, atọkunrin atobinrin, bẹ̀rẹ̀ sí tako àwọn Juu, arakunrin wọn. 2 Àwọn kan ń sọ pé, “Àwa, ati àwọn ọmọ wa, lọkunrin…

NEHEMAYA 6

Wọ́n Dìtẹ̀ Mọ́ Nehemaya 1 Nígbà tí wọ́n sọ fún Sanbalati ati Tobaya ati Geṣemu ará Arabia ati àwọn ọ̀tá wa yòókù pé a ti tún odi náà mọ, ati…

NEHEMAYA 7

1 Lẹ́yìn tí a ti mọ odi náà tán, tí mo ti ṣe àwọn ìlẹ̀kùn rẹ̀, tí mo sì ti yan àwọn olùṣọ́ ẹnu ọ̀nà, ati àwọn akọrin ati àwọn…

NEHEMAYA 8

Ẹsira Ka Òfin fún Àwọn Eniyan náà 1 Ní ọjọ́ kinni oṣù náà, gbogbo wọn pátá péjọ pọ̀ sí gbangba ìta níwájú Ẹnubodè Omi, wọ́n sì sọ fún Ẹsira, akọ̀wé,…

NEHEMAYA 9

Àwọn Eniyan náà Jẹ́wọ́ Ẹ̀ṣẹ̀ Wọn 1 Ní ọjọ́ kẹrinlelogun oṣù kan náà, àwọn ọmọ Israẹli péjọ pọ̀, wọ́n gbààwẹ̀, wọ́n wọ aṣọ ọ̀fọ̀, wọ́n sì ku eruku sí orí…

NEHEMAYA 10

1 Àwọn tí wọ́n fi ọwọ́ sí ìwé náà tí wọ́n sì fi èdìdì dì í nìwọ̀nyí: Nehemaya, gomina, ọmọ Hakalaya, ati Sedekaya. 2 Lẹ́yìn náà, àwọn ọmọ alufaa wọnyi:…