NỌMBA 11

Ibi tí Wọn sọ ní Tabera 1 Nígbà tí ó yá àwọn eniyan náà bẹ̀rẹ̀ sí kùn sí OLUWA nípa ìṣòro wọn. Nígbà tí OLUWA gbọ́ kíkùn wọn, inú bí…

NỌMBA 12

Ìjìyà Miriamu 1 Miriamu ati Aaroni sọ̀rọ̀ òdì sí Mose nítorí pé ó fẹ́ ọmọbinrin ará Kuṣi ní iyawo. 2 Wọn ń wí pé, “Ṣé Mose nìkan ni OLUWA ti…

NỌMBA 13

Mose Rán Amí lọ sí Ilẹ̀ Kenaani 1 OLUWA sọ fún Mose pé, 2 “Rán amí lọ wo ilẹ̀ Kenaani tí mo fún àwọn ọmọ Israẹli. Ẹnìkọ̀ọ̀kan tí ó bá…

NỌMBA 14

Àwọn Eniyan náà Kùn 1 Gbogbo àwọn eniyan bẹ̀rẹ̀ sí ké, wọn sì fi gbogbo òru ọjọ́ náà sọkún. 2 Gbogbo wọn ń kùn sí Mose ati Aaroni pé, “Ó…

NỌMBA 15

Àwọn Òfin nípa Ìrúbọ 1 OLUWA sọ fún Mose pé, “Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, 2 bí ẹ bá dé ilẹ̀ tí mo fún yín láti máa gbé, 3…

NỌMBA 16

Ọ̀tẹ̀ tí Kora, Datani ati Abiramu Dì 1 Kora ọmọ Iṣari láti inú ìdílé Kohati ọmọ Lefi, pẹlu Datani ati Abiramu àwọn ọmọ Eliabu, pẹlu Ooni ọmọ Peleti láti inú…

NỌMBA 17

Ọ̀pá Aaroni 1 OLUWA sọ fún Mose pé, 2 “Gba ọ̀pá mejila láti ọwọ́ àwọn ọmọ Israẹli, ọ̀pá kọ̀ọ̀kan láti ọwọ́ olórí ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan, kí o sì kọ orúkọ olukuluku…

NỌMBA 18

Iṣẹ́ Àwọn Alufaa ati Àwọn Ọmọ Lefi 1 OLUWA sọ fún Aaroni pé, “Ìwọ, ati àwọn ọmọ rẹ, ati ìdílé baba rẹ ni yóo jìyà ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n bá dá…

NỌMBA 19

Eérú Mààlúù Pupa náà 1 OLUWA sọ fún Mose ati Aaroni pé, 2 “Ìlànà tí èmi OLUWA fi lélẹ̀ nìyí: Ẹ sọ fún àwọn ọmọ Israẹli kí wọ́n mú ẹgbọ̀rọ̀…

NỌMBA 20

Ohun Tí Ó Ṣẹlẹ̀ ní Kadeṣi 1 Ní oṣù kinni, àwọn ọmọ Israẹli dé aṣálẹ̀ Sini, wọ́n sì ṣe ibùdó wọn sí Kadeṣi. Níbẹ̀ ni Miriamu kú sí, tí wọn…