NỌMBA 31
Wọ́n Dojú Ogun Mímọ́ kọ Midiani 1 OLUWA sọ fún Mose pé, 2 “Fìyà jẹ àwọn ará Midiani fún ohun tí wọ́n ṣe sí àwọn ọmọ Israẹli. Lẹ́yìn náà, o…
Wọ́n Dojú Ogun Mímọ́ kọ Midiani 1 OLUWA sọ fún Mose pé, 2 “Fìyà jẹ àwọn ará Midiani fún ohun tí wọ́n ṣe sí àwọn ọmọ Israẹli. Lẹ́yìn náà, o…
Àwọn Ẹ̀yà Ìlà Oòrùn Jọdani 1 Nígbà tí àwọn ọmọ Reubẹni ati àwọn ọmọ Gadi, tí wọ́n ní ẹran ọ̀sìn pupọ, rí ilẹ̀ Jaseri ati ilẹ̀ Gileadi pé ibẹ̀ dára…
Ìrìn Àjò láti Ijipti sí Moabu 1 Ibi tí àwọn ọmọ Israẹli pàgọ́ sí ninu ìrìn àjò wọn láti ìgbà tí wọn ti kúrò ní Ijipti lábẹ́ àṣẹ Mose ati…
Àwọn Ààlà Ilẹ̀ náà 1 OLUWA sọ fún Mose pé, 2 “Pàṣẹ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, ‘Nígbà tí ẹ bá dé ilẹ̀ Kenaani tí mo fun yín, gbogbo ilẹ̀…
Àwọn Ìlú tí A Fún Àwọn Ọmọ Lefi 1 Ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Moabu ní ìhà ìlà oòrùn Jọdani ní òdìkejì Jẹriko, OLUWA sọ fún Mose pé, 2 “Pàṣẹ fún àwọn ọmọ…
Ogún Àwọn Obinrin Abilékọ 1 Àwọn olórí ìdílé àwọn ọmọ Gileadi, ọmọ Makiri ati ẹ̀yà Manase ọmọ Josẹfu, wá sọ́dọ̀ Mose ati àwọn olórí ẹ̀yà Israẹli, 2 wọ́n ní, “OLUWA…