ORIN DAFIDI 1
Ayọ̀ Tòótọ́ 1 Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni náà tí kò gba ìmọ̀ràn àwọn eniyan burúkú, tí kò bá àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ rìn, tí kò sì bá àwọn ẹlẹ́gàn kẹ́gbẹ́. 2…
Ayọ̀ Tòótọ́ 1 Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni náà tí kò gba ìmọ̀ràn àwọn eniyan burúkú, tí kò bá àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ rìn, tí kò sì bá àwọn ẹlẹ́gàn kẹ́gbẹ́. 2…
Àyànfẹ́ Ọlọrun 1 Kí ló dé tí àwọn orílẹ̀-èdè fi ń bínú fùfù tí àwọn eniyan ń gbìmọ̀ asán? 2 Àwọn ọba ayé kó ara wọn jọ, àwọn ìjòyè gbìmọ̀…
Adura ìrànlọ́wọ́ lówùúrọ̀ 1 OLUWA, àwọn ọ̀tá mi pọ̀ pupọ! Ọ̀pọ̀ ni ó ń dìde sí mi! 2 Ọpọlọpọ ni àwọn tí ń sọ kiri pé, Ọlọrun kò ní gbà…
Igbẹkẹle OLUWA 1 Dá mi lóhùn nígbà tí mo bá pè ọ́, Ọlọrun mi olùdániláre. Ìwọ ni o yọ mí nígbà tí mo wà ninu ìpọ́njú, ṣàánú mi, kí o…
Adura Ààbò 1 Fetí sí ọ̀rọ̀ mi, OLUWA; kíyèsí ìmí ẹ̀dùn mi. 2 Fetí sí igbe mi, Ọba mi ati Ọlọrun mi, nítorí ìwọ ni mò ń gbadura sí. 3…
Adura nígbà ìyọnu 1 OLUWA, má fi ibinu bá mi wí; má sì fi ìrúnú jẹ mí níyà. 2 Ṣàánú mi, OLUWA, nítorí àárẹ̀ mú ọkàn mi, OLUWA, wò mí…
Ọlọrun Onídàájọ́ Òdodo 1 OLUWA, Ọlọrun mi, ìwọ ni mo sá di; gbà mí là, kí o sì yọ mí lọ́wọ́ àwọn tí ń lépa mi. 2 Kí wọn má…
Ògo OLUWA ati Ipò Eniyan 1 OLUWA, Oluwa wa, orúkọ rẹ níyìn pupọ ní gbogbo ayé! Ìwọ ni o gbé ògo rẹ kalẹ̀ lókè ọ̀run. 2 Àwọn ọmọ-ọwọ́ ati àwọn…
Ọpẹ́ fún Ọlọrun nítorí Ìdájọ́ Òdodo Rẹ̀ 1 OLUWA, tọkàntọkàn ni n óo fi dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ; n óo ròyìn gbogbo iṣẹ́ ìyanu rẹ. 2 N óo yọ̀, inú mi…
Adura Olùpọ́njú 1 Kí ló dé tí o fi jìnnà réré, OLUWA, tí o sì fara pamọ́ ní ìgbà ìpọ́njú? 2 Pẹlu ìgbéraga ni eniyan burúkú fi ń dọdẹ àwọn…