ORIN DAFIDI 91

Ọlọrun Aláàbò wa 1 Ẹni tí ń gbé abẹ́ ààbò Ọ̀gá Ògo, tí ó wà lábẹ́ òjìji Olodumare, 2 yóo wí fún OLUWA pé, “Ìwọ ni ààbò ati odi mi,…

ORIN DAFIDI 92

Orin Ìyìn 1 Ó dára kí eniyan máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, OLUWA; kí ó sì máa kọ orin ìyìn sí orúkọ rẹ, ìwọ Ọ̀gá Ògo; 2 ó dára kí eniyan…

ORIN DAFIDI 93

Ọlọrun Ọba 1 OLUWA jọba; ó gbé ọlá ńlá wọ̀ bí ẹ̀wù; OLUWA gbé ọlá ńlá wọ̀, ó sì di agbára ni àmùrè. Ó fi ìdí ayé múlẹ̀; kò sì…

ORIN DAFIDI 94

Ọlọrun Onídàájọ́ Gbogbo Ayé 1 OLUWA, ìwọ Ọlọrun ẹ̀san, ìwọ Ọlọrun ẹ̀san, fi agbára rẹ hàn! 2 Dìde, ìwọ onídàájọ́ ayé; san ẹ̀san èrè iṣẹ́ àwọn agbéraga fún wọn! 3…

ORIN DAFIDI 95

Orin Ìyìn 1 Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á kọrin sí OLUWA; ẹ jẹ́ kí á hó ìhó ayọ̀ sí Olùdáàbòbò ati ìgbàlà wa! 2 Ẹ jẹ́ kí á wá…

ORIN DAFIDI 96

Ọlọrun Ọba Àwọn Ọba 1 Ẹ kọ orin titun sí OLUWA; gbogbo ayé, ẹ kọ orin sí OLUWA. 2 Ẹ kọ orin sí OLUWA, ẹ yin orúkọ rẹ̀; ẹ sọ…

ORIN DAFIDI 97

Ọlọrun Ọba Atóbijù 1 OLUWA jọba, kí ayé ó yọ̀; jẹ́ kí inú ogunlọ́gọ̀ erékùṣù ó dùn. 2 Ìkùukùu ati òkùnkùn biribiri ni ó yí i ká; òdodo ati ẹ̀tọ́…

ORIN DAFIDI 98

Ọlọrun, Ọba gbogbo Ayé 1 Ẹ kọ orin titun sí OLUWA, nítorí tí ó ti ṣe ohun ìyanu; agbára ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀, ati apá mímọ́ rẹ̀ ni ó fi ṣẹgun….

ORIN DAFIDI 99

Ọlọrun Ọba Atóbijù 1 OLUWA jọba, kí àwọn orílẹ̀-èdè wárìrì; ó gúnwà lórí àwọn kerubu; kí ilẹ̀ mì tìtì. 2 OLUWA tóbi ní Sioni, ó sì jọba lórí gbogbo orílẹ̀-èdè….

ORIN DAFIDI 100

Orin Ìyìn 1 Ẹ hó ìhó ayọ̀ sí OLUWA, gbogbo ilẹ̀ ayé. 2 Ẹ fi ayọ̀ sin OLUWA. Ẹ wá siwaju rẹ̀ pẹlu orin ayọ̀. 3 Ẹ mọ̀ dájú pé…