ORIN DAFIDI 101
Ìlérí Ọba 1 N óo kọrin ìfẹ́ ati ìdájọ́ òdodo, OLUWA, ìwọ ni n óo máa kọrin ìyìn sí. 2 N óo múra láti hu ìwà pípé pẹlu ọgbọ́n; nígbà…
Ìlérí Ọba 1 N óo kọrin ìfẹ́ ati ìdájọ́ òdodo, OLUWA, ìwọ ni n óo máa kọrin ìyìn sí. 2 N óo múra láti hu ìwà pípé pẹlu ọgbọ́n; nígbà…
Adura Olùpọ́njú 1 Gbọ́ adura mi, OLUWA; kí o sì jẹ́ kí igbe mi dé ọ̀dọ̀ rẹ. 2 Má yọwọ́ lọ́ràn mi lọ́jọ́ ìṣòro! Dẹtí sí adura mi; kí o…
Ìfẹ́ Ọlọrun 1 Yin OLUWA, ìwọ ọkàn mi, fi tinútinú yin orúkọ rẹ̀ mímọ́. 2 Yin OLUWA, ìwọ ọkàn mi, má sì ṣe gbàgbé gbogbo oore rẹ̀, 3 ẹni tí…
Yíyin Ẹlẹ́dàá 1 Yin OLUWA, ìwọ ọkàn mi, OLUWA, Ọlọrun mi, ó tóbi pupọ, ọlá ati iyì ni ó wọ̀ bí ẹ̀wù. 2 Ó fi ìmọ́lẹ̀ bora bí aṣọ, ó…
Ọlọrun ati Àwọn Eniyan Rẹ̀ 1 Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, ẹ pe orúkọ rẹ̀, ẹ fi iṣẹ́ rẹ̀ hàn ní gbogbo orílẹ̀-èdè. 2 Ẹ kọrin sí i, ẹ kọ orin…
Oore OLUWA fún Àwọn Eniyan Rẹ̀ 1 Ẹ yin OLUWA! Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, nítorí pé ó ṣeun nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae. 2 Ta…
Yíyin OLUWA fún Oore Rẹ̀ 1 Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, nítorí pé ó ṣeun, nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae. 2 Kí àwọn tí OLUWA ti…
Adura Ìrànlọ́wọ́ láti Borí Ọ̀tá 1 Ọkàn mi dúró ṣinṣin, Ọlọrun ọkàn mi dúró ṣinṣin. N óo kọrin, n óo sì máa yìn ọ́. Jí, ìwọ ọkàn mi! 2 Ẹ…
Ìráhùn Ẹni tí Ó Wà ninu Ìṣòro 1 Má dákẹ́, ìwọ Ọlọrun tí mò ń yìn. 2 Nítorí pé ẹnu àwọn eniyan burúkú ati ti àwọn ẹlẹ́tàn kò dákẹ́, wọ́n…
OLUWA ati Àyànfẹ́ Ọba Rẹ̀ 1 OLUWA wí fún oluwa mi, ọba, pé, “Jókòó sí apá ọ̀tún mi, títí tí n óo fi sọ àwọn ọ̀tá rẹ di àpótí ìtìsẹ̀…